SW/Prabhupada 0008 - Krsna Claims That 'I Am Everyone's Father'



Janmastami Lord Sri Krsna's Appearance Day Lecture -- London, August 21, 1973

Bee ni, o kereju ni orilè ede India, gbogbo awon eniyan pataki, eniyan mimô, awon ôlôgbôn aye ati awon olulana, won ti fi imo ijinlè yii se wa wu ni dara dara ati ni ikunkun, sugbon awa o ka kun. Kii se wipe awon ara India, tabi awon Hindus, abi awon brahmanas nikan ni a won iwe mimô, śāstras, ati ilana won yi wa fun. Won wa fun eni kô kan wa. Nitori Olorun fi ba lè pe

sarva-yoniṣu kaunteya
sambhavanti mūrtayaḥ yaḥ
tāsāṁ mahad brahma yonir
ahaṁ bīja-pradaḥ pitā
(BG 14.4)

Olorun fi ba lè pe "emi ni Baba ohun gbogbo." Nitorina, Oun se oseju lôpôlôpô lati munu wa dun, ati fi okan wa ba lè. Gègè bi baba ômô se fè ri ômô rè ni po to dara ati layô, bakanna, Olorun naa fè ri èni kô kan wa layô ati ni po to dara. Nitori eyi, Oun fun ra rè sô ka lè wa, lèè kô kan. (BG 4.7) Yadā yadā hi dharmasya glānir bhavati. Eyi ni idi rè ti Olorun fi sô ka lè wa, gègè bi Krishna. Nitorina awon ti won se iranse Krishna, awon ômô lèyin Krishna, won ni lati gba ise Olorun pataki. Won ni lati gbe ise Olorun pataki na ga. Eyi ni ijèmu Chaitanya Mahaprabhu

āmāra ajñāya guru hañā tāra ei deśa
yare dekha, tare kaha, 'kṛṣṇa'-upadeśa
(CC Madhya 7.128)

Kṛṣṇa-upadeśa. E gbiyanju ati se iwasu ohun ti Olorun ti so ninu iwe mimo Bhagavad Gita Eyi ni oju isè gbogbo awon ômô orilè ede India Caitanya Mahāprabhu so wipe.

bhārata-bhūmite manuṣya janma haila yāra
janma sārthaka kari para-upakāra.
(CC Adi 9.41)

Nitorina awon Indiana, awon ômô ori lè ede Indian a se won fun para-upakara. Kiise isè won lati jéré isè awon èlo miran. Iyen kiise isè oro-aje won. Itan idilè India lati igba lai lai wa fun para-upakāra. Ati pe nigba kan tèlè, lati gbogbo ori édé aye, ni awon eniyan ti nwa si India lati kô imoran ijinlè nipa ôrô èmi. Jesu Kristi pàapà na lô si bè. Ati lati orilè édé China ati awon orilè édé miran. Eyi je itan. A si wa ngba gbe nkan ibilè wa ti o jô ju. Iyen fi han bi a se ni okan lile si. Iru ègbè nla gidi yi, ti imôlè Olorun, o nfi èsè mu lè kaa kiri gbogbo aye, sugbon awon ômô orilè édé wa ni India ni okan lile, awon ijoba wa na ni okan lile. Won o gba. Iyen ni abosi wa. Sugbon isè pataki ti Chaitanya Mahaprabhu ni yi. O sô wipe èni to ba jè ômô India, bhārata bhūmite manuṣya janma, ti o ba jè ômô eniyan, o gbôdô se aye rè yégé ni pa awon ilana ti iwe mimô Vèdiki. ko si se ikédé imô naa ni orilè ede gbogbo kari aye. Eyi lo tumô si para-upakāra. Bee ni orilè édé India léé sé. Nwon fi iyi fun ni tootô. Awon oyibo yii, ati awon ôdômôkunrin Amèrika won yi, nwon fi iyi fun wipe bi ose wa to... Mo ngba ôpôlôpô iwe iranse nipa bi awon eniyan nse nri anfaani ni pa ti isè ijô wa. Nitootô, ododo ni eyi. O nfi èmi fun awon ti won ti dabi oku. Nitorina, ibeere mi pataki fun awon ômô orilè édé India, pataki julô, Olori Alaasè, E jôwô è farapô mô ègbè yi, ki è si se ile aye yin ati ti awon miran ni ase yô ju. Eleyi ni ise Olorun pataki, ti O fi sô ka lè wa gege bi Krishna. E sé pupô. (Ipatewo)