YO/Prabhupada 0030 - Krishna kan ngbadun



Sri Isopanisad, Mantra 2-4 -- Los Angeles, May 6, 1970

Olorun Baba loke, bi o ti le je wipe O wa ni oju kan ni ibugbe Re, o ni yara ju okan lo o si le yara ju gbogbo awon ti oun sare. Awon alagbara angeli ko le su mo. Bi O ti le wa ni oju kan, O ni ase lori awon ti onse afefe, ati ojo, O ju gbogbo eda lo ni gbogbo didara" Eyi na tun je titenumo ninu Brahma-samhita: goloka eva nivasaty akhilātma-bhūtaḥ (Bs. 5.37). Bi o ti le je wipe ni gbogbo igba, Olorun wa ni Goloka Vrnadava, ko si nkan kan fun lati se. O kan ngbadun sa ninu egbe awon omo leyin re, awon gopi ati awon omo olusoagutan, Mama ati Baba re. Ominira, ominira pata pata. Ati awon ti nse akoso re, bakanna na ni awon na se ni ominira pupo si. Nitoripe ni igba ti awon elegbe re ba wa ninu ewu, a di ironu fun Olorun ni pa bawo ni lati gba won sile, sugbon awon elegbe re, awon ko ni ironu kan kan. " Ah Olorun wa nbe" E ri beyen [erin] Awon elegbe re, won ko ni ironu kan kan. Nkan ki nkan ti oun sele, e ma ri ka ninu iwe Krishna - aimoye ewu. Awon omokunrin, pelu Krishna, won ma nlo pelu awon omo malu ati awon malu lati lo sere ninu Igbo ni igbegbe odo Yamuna, bee na ni Kamsa ma ran awon elesu lati lo se won lese. E ti ri won ba yen, e ma ri awon aworan na, Bayi ni won se ngbadun nitori pe won ni igbokon le pupo. Iyen ni ile aye ti emi. Avaśya rakṣibe kṛṣṇa viśvāsa pālana. Igbagbo to lagbara yi, wipe "Ninu ewu kewu, Krishna a gba mi la,"

Ipa ese mefa ati jowo ara ni lo wa. Nkan akoko nipe a gbodo gba eyi ti o ma se wa la anfani fun ise Oluwa; a si ma ko nkan ki nkan ti ko ba wa la anfani fun ise Oluwa. Eyi ti o tun tele ni wipe a gbodo fi ara wa han niwaju awon ti won nse akoso ti Oluwa Olorun. Gege bi Krishna se ni opolopo awon oluranwo, e le se... Iyen a, ka ma wi oun miran... Ki ise toju lasan. Ni igba ti e ba lo si waju si o ma ye yin kini ibatan yin pelu Olorun. Ni bee na ti e ba fi ara yin han ni pa bi e se je, bayi ese to tele ni igboya pe "Krishna ma da abo bo mi" Daju daju, O nfun oni kalu ku ni idabobo. Iyen ti daju. Sugbon ninu aimokan a ro wipe a nse idabobo ara wa, a nfi ounje fun ara wa. Rara. Iyen ko nse be.