YO/Prabhupada 0120 - Agbara idan awamaridi



Morning Walk At Cheviot Hills Golf Course -- May 17, 1973, Los Angeles

Prabhupāda: Ṣe o ti se nitúmọ abi?

Svarūpa Dāmodara: Awamaridi?

Prabhupāda: Awamaridi tabi ohun ijinle asiri.

Svarūpa Dāmodara: Agbara idan?

Prabhupāda: Beeni.

Svarūpa Dāmodara: Mo n kan gba ohun tí Śrīla Prabhupāda salaye, orisirisi awọn acintya-śaktis ti a se akiyesi.

Prabhupāda: Nibi ni acintya-śakti naa ti nṣiṣẹ, owusuwusu yi, kurukuru. Eyin o l'agbara lati le kuro. O Kọja agbara rẹ. Ele gbiyanju lati s'alaaye bo seri...

Eniyan ti o n'koja: E karo.

Prabhupāda: E karo. ti "Iru kemikali, iru ohun, iru ara yi, t'ohun" ọpọlọpọ awọn nǹkanni o wa . Ṣugbọn (nrerin) e ko ni agbara lati lé o kuro.

Svarūpa Dāmodara: Beeni. Won ni ohun alaye bi owusuwusu ti wa ni akoso. Nwọn pe ni...

Prabhupāda: Eyin na lese. Ìyẹn ni pé, emi na tun le ṣe . Kì nse nkan nla gan. Ṣugbọn ti o ba mọ bi o ti wa ni akoso, e gbiyanju nigbana lati yipada.

Svarūpa Dāmodara: A mọ bi o ti wa ni akoso. A mọ bi o ti wa ni akoso.

Prabhupāda: Beeni. Ti e ba mo, o ye ki e se awari lati le yipada. O kan dabi tẹlẹ, nigba ogun ti wọn nju awọn atomiki brahmāstra. Lona miiran... brahmāstra tumo si ooru to rékoja àlà. Nítorí náà, wọn mu ki nkan ṣẹlẹ , nwọn si yipada sinu omi Nitori lẹhin ooru, omi gbọdọ wa nibẹjẹ . Nibo ni iru sayensi na wa?

Svarūpa Dāmodara: O kan dabi wara. Wara wulẹ funfun, sugbon omi lo kan jẹ. Nwọn pè ni , ni a colloidal idaduro ti awọn ọlọjẹ, awon amuradagba, ninu omi. Nítorí bakanna, ikurukuru kan jẹ colloidal idaduro ti omi ninu awọn afẹfẹ ni.

Prabhupāda: Bẹẹni. Ki o ṣi da nà diẹ . Lẹsẹkẹsẹ ni o ma lé wọn kuro. Omi le se lé kuro pelu inà . Ki e ṣi da nà. Kolese se funyin. O kan yin bombu kan.. Ooru diẹ yio si wà, ati gbogbo awọn owusuwusu yi yio lọ kuro. Ṣe.

Karandhara: Eleyi ma fina si gbogbo isọgbe-aye. Eleyi ma fina si gbogbo isọgbe-aye.(Erin)

Prabhupāda: Hare Kṛṣṇa. A le se iro omi pelu inà tabi afẹfẹ. Gbogbo eniyan lo mo. Nitorina iwọ se o, idaduro. Agbara idan leleyi je funyin. O le sọrọ gbogbo awọn isọkusọ, ṣugbọn iwọ ko le ṣe lòdì . Nitorina agbara idan loje fun yin. Bẹ bakanna, ọpọlọpọ awọn nkan ni o wa. Ìyẹn ni acintya-śakti... Ti e ko le lero paapa. Nipa ona iseda, lẹsẹkẹsẹ ti oorun ran - ko si owusuwusu mọ. Gbogbo e ti pari. Ti iwonba orun ton ran ba dide soke, gbogbo e ti pari. Nīhāram iva bhāskaraḥ. Iwe Bhagavata ti fun wa ni iru apeere yi. Nīhāra a npe. Gege bi nīhāra se nkase mole lesekese nipa bhāskara, nipa oorun, bakanna, ti eniyan ba le ji ise-deede esin re ti o fi yeku, gbogbo re pari niyen, gbogbo awon éré ese owo re, ti pari. Nīhāram iva bhāskaraḥ. E kan ṣẹda... O ṣe iṣiro oorun ni tiwon kemikali yi, ti kemikali t'ohun. E kan ṣẹda oorun eyọkan ki e si sọ sita. Jiroro nipa ojo iwaju, se idari pelu awon kobakungbe ọrọ, iyẹn ko dara.

Svarūpa Dāmodara: Eyi ni ohun ti iwadi tumo si. Iwadi tumo si lati ni oye ohun ti a kò mọ tele.

Prabhupāda: Bẹẹni. Iwadi tumo si ki o gba wipe gbogbo yin ni òmùgọ ati alaibikita. Iwadi wa fun taani? Eni ti kò mọ. Bibẹkọ ewo ni ibeere ti iwadi? Ko ye yin. Oyeke jewo. E fi ìrẹlẹjẹwọ. Opọlọpọ awọn agbara idan ni won wa nibẹ. Eyin ko mo bi o ti nse ṣee ṣe. Nitorina o ni lati gba agbara awamaridi. Ati laisi gbigba ofin ti agbara awamaridi yi, ko si ìtumọ Ọlọrun. Kii se bi wipe Bala-Yogi di Ọlọrun. Nitorina awọn wọnyi wa fun awọn alaibikita, awon òmùgọ. sugbon awon to logbon, won a dán agbara awamaridi na wo. O kan dabi gẹgẹ bi a se gba Krishna bi Ọlọrun - agbara awamaridi. A gba Rama - agbara awamaridi. Ko se bẹ wopo. Alaibikita kan wa o si wí pé," Èmi ni eya Olorun" awon asiwere mìíràn si gba. Kii se be lo ri . "Ramakrishna jẹ Ọlọrun." Awa kò gba. A gbọdọ ri agbara ijinle awamaridi. Gẹgẹ bi Krishna, bi ọmọde, se gbe oke giga. Eleyi jẹ agbara idan awamaridi. Rāmacandra, Rāmacandra, Oun ko Afara okuta laisi opo labe re. Awọn okuta bẹrẹ sí leefo: "Se Ẹ ri ." Bẹ nìyẹn se je ẹya agbara awamaridi. Ati nitori ti o ko ba le ṣatunṣe agbara awamaridi yi, nigbati nwọn ba se won ni apejuwe, iwo a wipe, "Iyen o, gbogbo awọn wọnyi itan ni." Kí ni a npe ? Itan aye atijọ. Ṣugbọn awọn ojogbon nla, nla wọnyi, Vālmīki ati Vyāsadeva ati awọn acharyas miiran, nwọn nìkan ṣòfo akoko wọn ni kikọ itan aye atijọ? Iru awon ọjọgbọn akẹkọọ? Ati ti wọn ko si tumo wipe o jẹ itan aye atijọ. Wọn ti gba bi abe ti o daju. Inu igbo si gbina. Gbogbo awọn ọrẹ ati oluso-agutan omokunrin, nwọn si dojuru. Nwọn si bẹrẹ si sare lọri Krishna: "Krishna, kini lati se?" "Ko buru." O kan gbe gbogbo inà na mi soke. Eyi ni agbara idan awamaridi. Iyen ni Olorun. Aiśvaryasya samagrasya vīryasya yaśasaḥ śriyaḥ (Viṣṇu Purāṇa 6.5.47). Awọn bukita mẹfa wọnyi ni kikun. Olorun niyen. Agbara awamaridi tabi agbara idan, awa na ni yen. Ni osunwon kinkinni gan. Opọlọpọ awon nkan ni won nsele ninu ara wa. A ko le se alaye. Apẹẹrẹ kanna. Eekanna mi nyo jade deede ni iwọn siwonsi. Biotilejepe o nse ibajẹ nipa arun, o si tun njade. Emi ko mo ohun ẹrọ ti o n sise, ti awọn ekanna ń yọ jade, ti won si nyẹ ipo won gégé ati ohun gbogbo. Ti o ti njade lati ara mi. Iyen jẹ agbara idan. Koda o je agbara idan fun mi, ati fun awọn dokita, gbogbo eniyan... Wọn ko le se alaye.