YO/Prabhupada 0142 - Fi ipari si iku yi



Lecture on SB 6.1.15 -- Denver, June 28, 1975

Awon oni oye nipa ipinnu aye. wan oosi rori wo nipa asiko ton wa. funa awon bayi kosi idayato laarin aye-ese ati aye-mimo. sugbon awon eyan lema nigbagbo ninu awon nkan bayi. teba si ni aisan lara, nigba die oma jade. teba nigbagbo tabi rara, kowulo. dokita saheb to wa nibi mo wipe teyan bani aisin lara nigba die aisan na ma jade. gege na awa ti ni awon ami idayato tole wora bi aisan. àmúyẹ meta lowa - sattva-guṇa, rajo-guṇa, tamo-guṇa - gege bi aisan wa seri gege na lawa mani ara toye. Karmaṇā daiva-netreṇa (SB 3.31.1). Gbogbo wa lan sise labe agbara ile-aye yi, gege bi abasepo wa seri, bayi na lama ni ara, tathā dehāntara-prāptiḥ (BG 2.13). kosi ile-iwe giga, tabi sayensi tole salaaye nipa nkan ton sele. Prakṛteḥ kriyamāṇāni guṇaiḥ karmāṇi sarvaśaḥ (BG 3.27). Prakṛti wa nibe.

Gbogbo wa lawa ninu aye yi nitori aisan tioda yi. Isoro wa leleyi. Agbudo ku. ohun ìdájú towa niyen. kosejo pe " mio ni'gbagbo ninu iku", gbafara koni ye. Iku gbudo wa, egbudo ku. Gege bayi ni ile-aye sen lo. sugbon pelu ara eda tani, ale yonju e. Eto imoye Krsna niyen, taba le ni iyipada lori asepo wa pelu awon ona ile-aye yi.. nitori asepo yi, lawa seni ibimo, nigba die atuma farale, lehin igbadie atun ni ibimo, atun ma farale. Agbudo fi'pari si eto yi. Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama (BG 15.6). Sugbon bakanna tabi awon kan, teba le pada si ijoba orun, yad gatvā, koni sejo pe ema pada. sugbon awon eyan bayi o mo wipe ile-aye yi kunfun ibanuje. wanti gbawipe, " O da gan". Eranko. Gege bi awon eranko towa ninu ile-iperan, awon erank si po gan, sugbon gbogbo wan lonma pa daanu. Gbogbo eyan mo, awon eranko gan mo. sugbon nitoripe eranko lonje kosi nkan ton lese. gege na, awa na wa ninu ile-iperan ile-aye yi. mṛtyu-loka ni oruko ile-aye yi. Gbogbo eyan mowipe wan ma fi kupa oun. Boya leni tabi ola tabi lehin odun aadota, tabi lehin odun ogorun, gbogbo wan mowipe nijokan agbudo ku. Eyan na ma ku. ìpànìyàn ni itumo Iku. Koseni to fe ku. Awon eranko gan, o fe ku. pelu agbara lon fi ku pa wan. ìpànìyàn leleyi. Gege na talofe ku? Koseni na. sugbon ofin iseda niyen ogbudo ku. Ile-iperan lawa. Ile-iperan ni gbogbo ile-aye yi. Agbudo ji soro na. mṛtyu-loka ni oruko ile-aye yi. Isoro to wa niyen. Sugbon awon eyan si gba lero bi awon eranko. Awon eranko o si mu oro na ni pataki, toba tie mo wipe wa fi ike pa, koni se nkankan.

Ipo wa niyen. Mṛtyu-saṁsāra-sāgarāt, Teṣām ahaṁ anukampārtham aham ajñāna-jaṁ tamaḥ. Teṣām ahaṁ samuddhartā mṛtyu-saṁsāra-sāgarāt (BG 12.7). agbudo ni oye nipa ipo wa. koseni tofe ku, sugbon asi ku na. lehin na wan si fun l'aye si, ara tunutun. Leyonkan si wa si pa danu. Ofin ile-aye yi niyen. Daivī hy eṣā guṇamayī mama māyā duratyayā (BG 7.14). Agbudo ni oye nipa basele fi'upari si iku yi. Ogbon leleyi. Bibeko, idunnu tama ni ma dabi awon aja ati ologbo, " Oh, moti jeun yo, moden fo soke. Kosejo ton ba pami danu," kosogbon ninu oro bayi. Ati fi ipaari si'ku ni ogbon gidi. Iru ogbon tawan salaaye niyen.

Eyan le jade ninu ile-iperan yi pelu ise-ifarafun Oluwa. wanti salaaye na, kecit kevalayā bhaktyā (SB 6.1.15). Kecit. Ko fibe wọpọ. O si le gan lati ri eyan to gba imoye Krsna yi s'okan. Kecit kevalayā bhaktyā. sugbon pelu ise ifarafun Oluwa ale jade kuro ninu ipo iku to lewu yi Kecit kevalayā bhaktyā (SB 6.1.15). tani awon eyan yi? Vāsudeva-parāyaṇāḥ, aawon elesin Kṛṣṇa. Vāsudeva ni Oruko Kṛṣṇa. Omo Vāsudeva loje; nitorina ni oruko re seje Vāsudeva. vāsudeva-parāyaṇāḥ. " Vasudeva ni ipinnu aye wa" ni itumo Parāyaṇāḥ vāsudeva-parāyaṇāḥ lon pe awon eyan yi. Vāsudeva-parāyaṇāḥ, aghaṁ dhunvanti. Ohun ibaji ni tumo Agham. Awa si feran awon ohun ibaje aye yi. taba di vāsudeva-parāyaṇāḥ... Vāsudevaḥ sarvam iti sa mahātmā sudurlabhaḥ (BG 7.19), nkankana loje. wansi salaaye pe kecit- itumo re niwipe o si le gan. lati ri. Kṛṣṇa salaaye ninu Bhagavad-gītā, vāsudevaḥ sarvam iti sa mahātmā sudurlabhaḥ (BG 7.19). Sudurlabhaḥ, o si le gan lati ri.