YO/Prabhupada 0149 - Lati monipa Baba wa l'orun n'idi fun egbe imoye Krishna yi



Tenth Anniversary Address -- Washington, D.C., July 6, 1976

Lati monipa Baba wa l'orun ni'id fun egbe imoye Krsna yi. Baba to gaju. Ipari oro egbe wa niyen. tawa o ba mo eni ti baba wa je, nkan tio da niyen. Ni orile-ede India teyan o ba mo oruko Baba re, awoneyan oni fun l'aponle. ilana to wa ni Ile-idajo niwipe teyan ba ko oruko re, ogbudo ko oruko baba re. Ilana Veda ati India niwipe eyan gbudo ko oruko re, oruko baba re ati oruko abule toti wa. Nkan meta yi papo. Awon Orile-ede toyato si India na tin se, sugbon Ilana India niyen. Oruko re ni t'alakoko, sugbon Baba re loni ikeji, Oruko abuloe toti wa ni iketa. ilana towa niyen. Agbudo mo baba wa. Egbe Imoye Krsna niyen. Taba gbagbe eni ti baba wa baje, nkan tio da niyen. Iru baba wo lan so? Paraṁ brahma paraṁ dhāma (BG 10.12). Eyi to lowo ju. Konse eyi tio lowo lati toju awon omo. Iru baba yi ko lawan so. Eko yo bahūnāṁ vidadhāti kāmān. baba yi lowo toje pe oun lon pese ounje fun aimoye wda. Ni Orile-ede Africa aimoye erin ton fun lounje. ninu yara yi awon kokoro towa ninu iho, oun na lon fun wan lonje. Eko yo bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). Iroyin Veda niyen.

Lati mo eni ti baba wa je ni idi fun igbese aye yi, kini ofin re, tal'Olorun je, kini abasepo tani pelu re. Vedanta leleyi. konsepe ka soro iranu, Vedanta koniyen. Śrama eva hi kevalam. Teyin o ba mo eni ti baba yin je..

dharmaḥ svanuṣṭhitaḥ puṁsāṁ
viṣvaksena-kathāsu yaḥ
notpādayed yadi ratiṁ
śrama eva hi kevalam
(SB 1.2.8)

Awa o fe yen. Krsna de sowipe, vedaiś ca sarvair aham eva vedyaḥ (BG 15.15). Ele di Vedantisit, nkan to da niyen. Ni bere Vedanta, wa sowipe lati Otito to gaju ni gbogbo nkan tin wa. Athāto brahma jijñāsā. Ibere niyen. Lati mo nipa Otitito to gaju ni'di fun ile aye yi, jijñāsā. Eyan gbudo mo nipa enito gaju ninu gbogbo agbaye. Itumo ile aye eda niyen, lati s'ebeere. Kini gbogbo nkan iyoku waje? Nkan meji lama ri: awon nkan pl'ei ati awon nkan tio l'emi. Irisi to daju. Awon imi l'emi awon kan o l'emi. Nkan meji. Nisin a le fe awon isasoto orisisiri to wa. Nkan mi niyen, sugbon nkan meji lowa. Asi leri wipe Olori wa lori gbogbo awon nkan yi, awon nkan pe'l'emi ati awon tio ni. nisin agbudo sebere lori orisun awon nkan meji wanyi, ipo wo loni? Iwe Śrīmad-Bhāgavatam ti salaaye, janmādy asya yato 'nvayād itarataś cārtheṣv abhijñaḥ (SB 1.1.1). Idaaun to wa niyen.

Orisun t'alakoko gbogbo nkan ni abhijñaḥ. Bawo? Anvayād itarataś cārtheṣu. ti mo ba da nkan sile mosi mo gbogbo nkan nipa re. Anvayād, boya taara tabi aiṣetaara, gbogbo nkan to wa nipa nkan timo da ni mo mo. Kasowipe mo mounje se, itumo re niwipe mo le salaaye bon sen se. Orisun to wa niyen. Krsna ni orisun yi. Krsna sowipe, vedāhaṁ samatītāni: (BG 7.26) " Gbogbo nkan nimo mo - totikoja, tisin, ati ti ojo iwaju". Mattaḥ sarvaṁ pravartate. Aham ādir hi devānām (BG 10.2). gege bi iroyin ohun ìdájú nipa iseda.. Brahmā viṣṇu maheśvara. awon devata to se pataki leleyi. Visnu ni olori wan. Aham ādir hi devānām. Ninu Iseda, Maha-Visnu lo bere; lehin Maha-Visnu ni Garbhodakaśāyī Viṣṇu. Lati Garbhodakaśāyī Viṣṇu ni Kṣīrodakaśāyī Viṣṇu tiwa lati Visnu lat'oun ni Brahma tiwa. Latinu òdòdó lotus to wa lati Garbhodakaśāyī Viṣṇu ni Brahma tijade, oun losi bi Rudra. Iroyin iseda niyen. Krsna says aham ādir hi devānām. Oun na ni Orisun Visnu nitoripe ninu sastra a mowipe kṛṣṇas tu bhagavān svayam (SB 1.3.28). Krsna ni eda alakoko Baladeva ni eda talakoko totinu Krsna wa. latoun ni Catur-vyūha, Vāsudeva, Saṅkarṣaṇa, Aniruddha, tiwa. Lehin Narayana awon Catur-vyuha keji, lati Catur-vyuha ikeji ni Sankarsana, Maha-Visnu. Bayi loyeke ko nipa sastra. Eyin na ma riwipe ninu sastra wan sowipe, kṛṣṇas tu bhagavān svayam. Krsna si sowipe, aham ādir hi devānām (BG 10.2). Ahaṁ sarvasya prabhavo mattaḥ sarvaṁ pravartate (BG 10.8). Arjuna si gbawipe, paraṁ brahma paraṁ dhāma pavitraṁ paramaṁ bhavān (BG 10.12). agbudo gba oro sastra. Śāstra-cakṣuṣāt: Egudo riran pelu oju sastra. Teba ko nipa sastra, ema riwipe kṛṣṇas tu bhagavān svayam.

Itumo egbe wa ni wipe afe fi Olorun han awon eyan. Egbe imoye Krsna niyen. NI odun 1966 la bere egbe na. Rūpānuga Prabhu ti salaaye pe emu oro egbe yi ni pataki. Egbe kanna ni Krsna bere ni odun ẹgbẹ́ẹdọ́gbọ̀n tokoja. pelu Arjuna toje akeko re, lo bere egbe yi lehin na Caitanya Mahāprabhu, tun egbe yi da ni odun ogorun marun to koja. Krsna loje fun ara re. Nkan ton sele niyen. Ema rowipe egbe ta kon daale leleyi. Rara. Egbe to daju leleyi awon olori si jerisi. Mahājano yena gataḥ sa panthāḥ (CC Madhya 17.186). wansi soro nipa awon mahājana niu sastra. E foju si egbe imoye Krsna yi kesi gbiyanju lati ni oye nipa re. Awa sini orisirisi iwe to daju tele ka teba fe ki ile-aye yin ni ilosikwaju.

Ese pupo.