YO/Prabhupada 0162 - E se waasu lori awon oro ti Bhagavad-gita



Press Interview -- October 16, 1976, Chandigarh

Prabhupāda: Ni orile-ede India awa ni iwe Veda to po lati ni oye nipa ise emi. sugbon t'awa o ba lo ara eda eyan yi t'ani lati fi toju apa emi ninu aye wa, ipara-ẹni loje fun wa. Ilana ti gbogbo awon eyan pataki ti funwa ni Orile-ede India niyen. Awon Ācāryas bi... T'asiko wa.... Awon tonti koja, awon Ācāryas pataki bi Vyāsadeva ati awon imi. Devala. Opolopo awon ācāryas. ninu odun ẹgbẹrun marun ọgọrun orisirisi ācāryas loti wa, bi Rāmānujācārya, Madhvācārya, Viṣṇu Svāmī, ninu odun ogorun marun Oluwa Caitanya Mahāprabhu na tiwa.

Wan de ti funwa awon iwe to po gan nipa imoye eto emi. Sugbon lasiko tawayi awon eyan ti pa imoye yi segbekan. Gege na ifiranṣẹ Caitanya Mahāprabhu si gbogbo agbaye niyen. pe ki gbogbo yin di guru, Oluko lori eto emi. Bawo ni gbogbo awon eyan sele d'oluko ninu eto emi? Atidi Oluko ninu eto emi kokin se ise to rorun rara. Eyan gbudo ni alakowe toni ajé nipa ara re ati gbogbo nkan. Sugbon Caitanya Mahāprabhu ti fun wa ni agbekalẹ kekere yi, pe teba tele awon eko Bhagavad-gita dada ati wipe teba se'waasu lori eto Bhagavad-gita eledi guru. Awon oro ton lo ninu ede Bengali ni, yāre dekha, tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa (CC Madhya 7.128). Ise n'la ni lati di guru sugbon teba se' waasu lori awon oro ti Bhagavad-gita kesi gbiyanju lati fi daniloju gbogbo awon eyan teba pade, lehin na eledi guru. Gege nkan ti egbe imoye Krsna yi wa fun niyen. Awan gbiyanju lati fun awon eyan ni awon eko Bhagavad-gita lai fi nkankan kun.