YO/Prabhupada 0163 - Itumo esin ni awon ofin ati ilana t'Olorun ti funwa



Lecture on BG 4.3 -- Bombay, March 23, 1974

Lati pada si ijoba Orun ni'di fun igbese aye wa. Idi fun aye yi niyen. Awa ti wa sinu ile-aye yi. Iya sin je wa. Sugbon awa o mo nitoripe ati yode. gege bi awon eranko. Awa o de mo ipinnu aye yi. Iwe Bhagavad-gita ti juwe ipinnu aye yi: janma-mṛtyu-jarā-vyādhi-duḥkha-doṣānudarśanam (BG 13.9). Tawa ba ni oye wipe " Iyika ile-aye yi pelu ibimo, iku, ojo arugbo ati aisan, mio si fe iru awon nkan bayi..." Koseni to fe ku, sugbon Iku a si wa mu wa lo. Ko le ronu pe "Isoro timoni leleyi. Mio fe ku, sugbon dandan ni ki ku de." Isoro to wa leleyi. sugbon koseni to mo bonsen yonju e. Awon isoro towa fun igba die lon sa tele, awon isoro wanyi o kin se isoro toye ka sa tele. Basele fi'paari si iku, ibimo, ojo arugbo ati aisan. Isoro gidi to wa niyen. Afi tabani ominiran latinu ile-aye yi lale yonju awon isoro wanyi. Isoro wa niyen.

Gege na Krsna tun sowipe... Yadā yadā hi dharmasya glānir bhavati bhārata (BG 4.7). Dharmasya glāniḥ. itumo Glāniḥ ni nkan toti yi soodi. Awon tin da nkan wan sile gbogbo na pelu oruko esin, " Esin wa niyen." " Esin Hindu." " Esin Musulman lelelyi," "Esin onigbagbo Kristeni leleyi," tabi " Esin Buddha leleyi." Ati " Esin Sikh leleyi." Esin teleyi tabi tooun..." Wanti da orisirisi esin sile. sugbon dharmaṁ tu sākṣād bhagavat-praṇītam (SB 6.3.19) ni esin to daju. Itumo Esin ni awon ofin ati ilana t'Olorun ti funwa. Itumo Esin niyen. Isotunmo Esin to rorun gan ni: dharmaṁ tu sākṣād bhagavat-praṇītam (SB 6.3.19). Gege b'ijoba sen da awon ofin sile. Kosi besele da awon ofin teyin sile. Moti so teletele. Ijoba lon da awon ofin sile. Gege na Olorun lo da Esin sile. Teba gba esin Olorun, iyen ni esin tose pataki. Kiwani esin Olorun? Toba fe duro, wa duro sibi. Awon wa ton woran. Ema ri esin Olorun ninu Bhagavad-gītā, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). Esin Olorun niyen. "Efi gbogbo awon esin iranu yi sile. Edi elesin mi, ke teriba funmi". Itumo esin niyen.