YO/Prabhupada 0164 - Agbudo da varnasrama-dharma yi sile latile ran awon eyan lowo



Room Conversation Varnasrama System Must Be Introduced -- February 14, 1977, Mayapura

Hari-śauri: Sugbon ninu iwaasu Caitanya Mahāprabhu awa riwipe, o beere lowo awon eyan kon korin.

Prabhupāda: Kolese se fun awon eyan lasan.

Hari-śauri: Se nkan tole ni lati sofun awon eyan kon korin? Oun na loda orin kiko yi sile.

Prabhupāda: Sugbon taloma korin na? Taloma korin?

Satsvarūpa: Sugbon kosi basele ko wan ni ilana varṇāśrama ti awon eyan yi o ba le korin. Nkan to rorun ju leleyi.

Prabhupāda: Orin kiko yi ma wa nbe, sugbon eme rowipe awon eyan ma korin bi Caitanya Mahāprabhu. Ati korin fun igba mẹrindilogun sooro funwan. sugbon awon asiwere wanyi fe daabi Caitanya Mahāprabhu.

Satsvarūpa: Rara. Sugbon ton ba korin ton je prasada...

Prabhupāda: Orin kiko yi gbudo tesiwaju. Ko sooro pe a daduro. Sugbon agbudo da varṇāśrama-dharma yi sile latile ran awon eyan lowo.

Hari-śauri: Nkan timo roni wipe wan da orin kiko yi sile nitoripe ni asiko Kali ta wayi, O sooro lati se varṇāśrama.

Prabhupāda: Orin kiko yi ma fo okan yin mo. Kosejo pe a fe daduro.

Hari-śauri: Gege na saale sowipe wan daa orin kiko yi sile latile ropo fun eto varṇāśrama

Prabhupāda: Beeni, A le rope e, sugbon taloma se? Awon eyan yi o fibe ni ilosiwaju . Teba farawe Haridas Thakura, tefe korin bonsen korin, Kolese se.

Satsvarūpa: Ale sofun pe ema sise ten se lo, sugbon ekorin na.

Prabhupada; Beeni. Thākaha āpanāra kāje, Bhaktivinoda Ṭhākura. Āpanāra kāja ki. Caitanya Mahāprabhu ti fun wa , sthāne sthitaḥ. ti awon eyan yi ba kuro ninu sthāna, igbana ni orin kiko bi awon sahajiyā ma bere. gege bi awon sahajiyā tonni ilẹkẹ yi sugbon wan ko awon obirin to po to merindilogoji. Iru orin kiko yi loma wa. Gege bi Madhudvisa, ko yeko gba sannyāsa sugbon o gba be. Asi riwipe o feran to obirin marun, o de so funwa. Nitori awon nkan bayi loye ka se varṇāśrama-dharma. Kole to tawa ba kon huwa lati farahan. Nitorina loye ke da varṇāśrama-dharma yi nigbogbo agbaye...

Satsvarūpa: Se ka bere pelu awon awujo ISKCON?

Prabhupada: Beeni. Beeni. Brāhmaṇa, kṣatriyas. Agbudo s'eto eko kiko.

Hari-śauri: Sugbon ninu awuo wa, ti ...., awa ti bere sini keko gege bi awon Vaisnavas...

Prabhupada; Beeni.

Hari-sauri: ... bawo lasefe pin awujo wa nigbana?

Prabhupada: Ati di Vaisanava kon se nkan to rorun. Agbudo da varnasrama-dharma yi sile tabafe di Vaisanava. Ko rorun atidi Vaisnava bayi.

Hari-sauri: Rara. Nkan to rorun ko leleyi.

Prabhupada: Beeni. Nitorina loyeka s'eto yi. Ati di Vaisnava ko kin se nkan to rorun. Toba yepe nkan to rorun ni kilode to jepe awon eyan ton yipada wa? Ko rorun rara. sannyāsa ni brāhmaṇa to gaju. Sugbon pe a kon wo'so Vaisnava, iyen koni koko oro.. ema yipada bayi.

Hari-śauri: Gege bi eto varṇāśrama je fun awon kaniṣṭhas, Kaniṣṭha-adhikārī.

Prabhupāda: Kaniṣṭha?

Hari-śauri: Mon soro fun awon eyan to alakobere.

Hari-śauri: Eto Varṇāśrama yi wulo fun gbogbo wa.

Prabhupāda: Itumo Kaniṣṭha-adhikārī niwipe ogbudo di brāhmaṇa. kaniṣṭha-adhikārī niyen. Ile aye emi, itumo kaniṣṭha-adhikārī, niwipe ogbudo di brāhmaṇa to daju. kaniṣṭha niyen. Nkan ti awon rope a dara gan ninu ile-aye yi, brāhmaṇa, kaniṣṭha-adhikārī niyen je