YO/Prabhupada 0176 - Krishna ma duro tiyin titi lailai teba ni'fe fun



Lecture on SB 1.8.45 -- Los Angeles, May 7, 1973

Awa sini agbara idan yi, sugbon awa o mo. Asi ni apeere fun. Oni agbọnrin toni lọfinda ton tinu idodo re jade, sugbon o fo kakiri, kakiri. Nibo ni lofinda yi tin wa? Ko mope lati inu idodo re lo tin jade. Se ri bayi. Lofinda yi wa ninu re, sugbon on wan kakiri, Nibo lowa> Nibo lowa? Beena ni gbogbo wa seni awon agabra idan ninu ara wa. Sugbon awa o mo. Sugbon teba ko awon ilana agbara ida yoga, awon imi ninu wan ma jade. gege bi awon eye ton fo, sugbon awa o le fo. Nigbami awa man ronu wi[e, " Tobajepe mo ni iyẹ apa eye... " Mo ma fo lo." sugbon agbara idan yi wa ninu wa. Teba jeko dagbasoke, eyin na le fo ni ofurufu. Olese se. Oni isogbe orun ton pe ni Siddhaloka. Ni Siddhaloka, awon olugbe, wan pe wan ni. Awon eyan pelu agbara idan nitumo Siddhaloka. Awa fe losi osupa pelu awon ero orisirisi. Awon eyan yi le fo. Lesekese ton ba fe lo, wan ma lo.

Gege na agbara idan yi wa ninu gbogbo eyan agbudo wa basele jeko dagbasoke. Parasya saktir vividhaiva sruyate (Cc. Madhya 13.65, purport). Awa ni orisirisi agbara idan to kon wa ninu wa, sugbon agbudo se ko dagba soke. gege bi odun merin si marun to koja eyin o mo eni ti Krsna je. Sugbon pelu ikeko eti bere sini mo eni ti Krsna je, eni t'Olorun je, ati iru ibasepo wo lani pelu re. Gege na ile aye eda wa fun iru ise bayi, kon se fun wiwa ounje, tabi ile, tabi imo ako ati abo. Awon nkan yi ti wa n'be tele. Tasyaiva hetoh prayateta kovido na labhyate... (SB 1.5.18). Koye ka ma waadi iru awon nkan bayi. Wanti wan'be tele. Awon eye ati awon eranko gan monipa r. se awon eda ni o le mo? sugbon wanti ya were toje pe. Nkan soso ton ro niwipe, nibo ni ounje wa, nibo ni ile wa, nibo ni imo ako ati abo wa, nigbo ni moti le gbeja ara mi. Awujo awon eyan tonti sonu, wanti sonu. Kosi'di fun awon nkan wanyi. Wan o le ri wipe awon eye at'eranko o ni aanfani mo. Kilode ti awon awujo eyan ma ni iru isoro bayi? Konse isoro rara. Isoro gidi tani ni basel fi ipaari si ibimo, iku, ojo arugbo at'aisan. Isoro gidi tani leleyi. Egbe imoye Krsna wa ti mu ona abay wa fun awon isoro wanyi. teba ni oye nipa eni ti Krsna je, tyaktva deham punar janma naiti (BG 4.9), kole si ibimo mo fun yin ninu ile-aye yi.

Egbe imoye Krsna yi da gan, teba le d'Ore peli Krsna, ele ba Krsna soro. gege bi Yudhisthira Maharaja se so: Krsna dakun duru pelu wa fun igba die si." Krsna a duro tiyin titi lailai teba ni'fe fun. Oma koja igba die.

Ese pupo.