YO/Prabhupada 0179 - Agbudo sise fun Krishna



Lecture on SB 1.16.6 -- Los Angeles, January 3, 1974

Awon alakowe Mayavadi wanyi le soro to po gan sugbon lehin igba die gbogbo wan loma wo lule. Kilode? Anadrta-yusmad-anghrayah: nitoripe wan o le ri idaabo yin gba, nitorina wan ma wo lule." Kosi idaabo kankan. Nitoripe koseni tole wa lai sen nkankan. Kolese se. Okurin, eranko, tabi kokoro gan, ogbudo ni nkan se. Moti foju mi ri. Ikan ninu awon omo mi, osi ni ijogbon to po nigbami ama fi sori aga. Nitorina kole sokale. Osi ni inira gan nitotirpe ko ri bi sere mo. kosi besele fi ipaari si awon ise teyin se. Kolese se. Egbudo se nkan imi. Lehin na lema paari. Param drstva nivartate (BG 2.59).

Gege lati ni nkan gidi se ni'ide fun imoye Krsna yi. Nitorina lose yeke fi awon ise iranu wanyi sile. Bibeko pe eyan yo okan kuro kole to. Agbudo sise. Agbudo sise fun Krsna. Agbudo losi ile- esin Krsna, tabi kalo ta awon iwe Krsna, tabi ka pade awon elesin Krsna. Nkan to da niyen. Sugbon kosi besele fi ipaari si ise sise. Kolese se. Nigbana opolo yin ma di ile-ise fun esu. Beeni. Lehin na ema wo lule, " bawole nimo sele ba obirin yi? Bawo nimosele ba okurin yi?" Teba fi ipaari si ise yin, egbudo tun sise lati le gbadun ara yin. Otan. Kosi besele fi ipaari si, sugbon ele lo ninu ise Oluwa. Imoye Krsna niyen