YO/Prabhupada 0183 - Owiwi, E dakun, E laa oju ke ri ina oorun



Lecture on SB 6.1.37 -- San Francisco, July 19, 1975

Olorun fun ara re ti wa sofun wa " Mo wa nibi. Moti wa." Paritranaya sadhunam vinasaya ca duskrtam (BG 4.8). " Moti farahan siyin lati fun yin ni itura." Paritranaya sadhunam. " Efe mo mipa mi, gege na mowa nibi. Moti wa. Kilode teyin se rowipe Olorun o ni irisi? Emi leleyi, Krsna Se ri, mo ni fere mi lowo. Mosi feraqn awon maalu gan. Mo feran awon maalu ati Brahma, gbogbo eyan nimo feran, nitoripe awon omo mi nigbogbo yin je." Krsna n'sere. Krsna n'sere. Sugbon, awon asiwere wanyi o le ni oye nipa Krsna. Kini alebu Krsna? Ejo wa loje. Andha. Gege bi eye owiwi. Eye owiwi o ni laju lati wo ina orun. Seyin mo eye owiwi? Koni laju. Kosi besele sofun to , " E dakun owiwi laju ko riran," Rara, kos'ina orun. mio le ri. " (Erin) Awujo owiwi niyen. Gege na egbudo ja pelu awon owiwi wanyi. Egbudo lagbara gan, nipataki awon sannyasi. Agbudo ja pelu awon owiwi yi. Agbudo laju wan pelu awon ero (erin) Nkan ton sele niyen. Gege na imoye Krsna yi ija lori awon owiwi loje.

Ipenija loje: yuyam vai dharma-rajasya yadi nirdesa-karinah. Nirdesa-karinah. Itumo iranse niwipe wan o ni ise imi ju kon sise fun oga wan. Nitorina loseje nirdesa-karinah. Kosi bonsele tiraka. Rara. Ounkooun tonba so funwan lonse. Gege na enikeni toba rowipe... wanti daruko awon Visnuduta na nibi, vasudevokt-karinah. Iranse na lonje' Gege na itumo ukta niwipe ti Vasudeva ba p'ase, wan jise. Gege na awon Yamaduta, iranse lonje si Yamaraja. nirdesa-karinah lonje: " Teyin ba je iranse si Yamaraja, egbudo se nkan toba so fun yin, lehin na egbudo mo nkan ti dharma baje ati nkan ti adharma ba je." Gege na iranse to daju lonje si Yamaraja, kosejo nibe. Nisin wanti funwa ni iadnimo wan bayi, yamaduta ucuh veda-pranihito dharmah, lesekese lon daun. "kini dharma?" Ibeere ton bere niyen. Lesekese lon daaun. Wan mo nkan ti dharma je. Veda-pranihito dharmah: " Itumo Dharma ni awon nkan ton ti salaaye ninu Veda." Kosi besele da dharma yin sile. Veda, imoye t'alakoko, Imoye ni Itumo Veda. Veda-sastra. Lati ibeere iseda, ni wanti fun Brahma ni awon Veda. Veda... Nitorina lon sen pe ni apauruseya; kon se nkan tele da sile. Wanti salaaye ninu iwe Srimad-Bhagavatam, tene brahma hrda adi-kavaye. Brahma, Veda ni'tumo brahma. Oruko imi fun Veda ni brahma, imoye mimo, tabi gbogbo imoye, brahma. Gege na brahma adi-kavaye hrda. Gege na agbudo keko awon Veda lodo Oluko mimo.

Gege na wanti salaaye wipe eda t'alakoko to ni oye Veda ni Brahma. Bawo lose ni oye na? Tani Oluko re? Koselomi nigbana. Bawo lose ni oye Veda? Krsna ni Oluko re, ode wa ninu oka re. Isvarah sarva-bhutanam hrd-dese arjuna tisthati (BG 18.61). Gege na on ko gbogbo wan latinu okan wan. Krsna de ti ko wa - Aanu re si wa po gan - bi caitya guru, latinu okan, asi ran awon iranse re lati ita. Caitya-guru ati guru, awon mejeji, Krsna si dara gan siwa. Gege na ele riwipe awon Veda yi o kin se awon iwe ti awon eyan ti da sile. Veda, apauruseya. Itumo Apauruseya niwipe nkan ton da sile ko loje... Awa o gbudo rowipe iwe lasan ti awon eyan kan da sile ni awon iwe Veda. Rara. Imoye to daju loje. Imoye to daju loje. Agbudo gba, gege bo seri lai fi nkankan kun, lai se isotunmo si. Olorun fun ara re lo s'oro iwe na. Nitorina Veda na ni Bhagavad-gita je. Krsna lo fun ara re so. Kosi besele fi nkan kun, tabi ke se isotunmo si. Egbudo gba gege boseje. Lehin na ele ni imoye to daju.