YO/Prabhupada 0188 - Ona abayo tayeraye si gbogbo isoro aye



Lecture on SB 2.3.17 -- Los Angeles, July 12, 1969

Visnujana: Prabhupāda, eti salaaye wipe Olorun ni'idi fun gbogbo nkan, sugbon koseni to mo Olorun, bawo ni awon lesele mowipe wan ni idari lori wan? Bawo lonsele mowipe wan labe enikan tio basi eni to mo Krsna oun de ni orisun gbogbo nkan? Bawo lonsele mo wipe nitori Krsna ni gbogbo nkan sen sele?

Prabhupāda: Bawo losele mo wipe o wa labe ijiba? Bawo losele mo?

Visnujana: ijoba ni iwe ofin.

Prabhupāda: Nitorina awa na ni awon iwe ofin. Anādi bahirmukha jīva kṛṣṇa bhuli gelā, ataeva kṛṣṇa veda-purāṇe karilā. Nitoripe etii gbagbe Krsna, Krsna ti funyin ni awon iwe to po, iwe mimo Veda. Nitorina ni monse salaaye ema lo asiko yin ni ilokulo lati ka awon iwe iranu wanyi. Ef'okan yin lori awon iwe Veda. Lehin na elemo. Kilode ti awon iwe yi se wa n'be? nLati ranyin leti pe egbudo tele awon ofin wanyi. Sugbon teyin o ba gba anfaani yi ni pataki, lehin na ilokulo lema lo aye yin. Ise iwaasu yi, itejade awon iwe yi, awon iwe, awon iwe iroyin, egbe imoye Krsna, gbogbo awon nkan yi wa lati ranwa leti pe awa labe awon nkan, tani oludaru to gaju yi, bi aye yin sele ni ilosiwaju, besele ni igbala lati ile-aye ton so, Besele ni'gbala. Egbe yi niyen. Idi fun egbe imoye Krsna yi niyen; bibeko kini iwulo egbe yi? Kon se awon ejo nla nla lati je ki inu awon eyan dun fun igba die. Ona abayo tayeraye si gbogbo isoro aye wa, egbe imoye Krsna yi. orin kiko yi loma jeki okan wa legba iwaasu yi. Ceto-darpaṇa-mārjanam (CC Antya 20.12), fifo okan wa. Lehin na ele ri iwaasu yi gba. Gege na ilana wa daju gege bi sayensi, enikeni to ba le se, die die loma ri wipe, oun tin ni ilosiwaju. Kosi iyemeji lori oro yi.