YO/Prabhupada 0192 - E yo gbogbo agbaye kuro ninu iho okunkun



Lecture on SB 6.1.62 -- Vrndavana, August 29, 1975

Ninu Bhagavad-gita wa salaye wipe, paraṁ brahma paraṁ dhāma pavitraṁ paramaṁ bhavān, puruṣaṁ śāśvatam adyam (BG 10.12). Wanti juwe Krsna bi purusa, ati awon eda bi prakrti. Apareyam itas tu viddhi me prakṛtiṁ parā, jīva-bhūto mahā-bāho yayedaṁ dhāryate jagat (BG 7.5). Krsna ti salaaye. Agbara ile-aye yi wa ati agbara mimo. gege na, jīva-bhūta. Jīva-bhūta, awon eda, Wanti juwe wan pe prakrti lonje, obirin nitumo prakrti. Wanti juwe Krsna bi purusa. Onigbadun ni purusa sugbon prakrti ni nkan ton gbadun. Ema rowipe imo ako ati abo ni igbadun tawan so .Rara. "Ton Gbadun" itumo re ni, lati jise purusa. E ronu ipo Krsna ati tawa. Nkankanna laje , gege bi ese ati owo je ikan pelu ara. Ise ese at'owo ni lati jise mi. Tin ba sofun ese i, " Gbe mi losi be." Lesekese loma se. Owo mi- " Mu nkan bayi." Owo asi mu nkan na. Prakrti ati purusa leleyi. Ti purusa ba p'ase, prakrti ma jise. Kon sepe lesekese taba soro nipa prakrti ati purusa, ema bere sini rowipe imo ako ati abo lan so. Rara. Itumo Prakrti niwipe o gboran si purusa. bose ye koje niyen. Ni ilu awon geesi wan fe se kon wa sori ipo kanna, sugbon kolese se. Kosejo pe eleyi gaju ikeji lo. Kosejo bayi. gege na, ni ibeere, yato vā imani bhūtāni jayante. Janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). Nibo ni ibasepo purusa ati prakrti yi ti beere? Janmādy asya yataḥ. Lati Otitio to gaju loti bere. Nitorina Rādhā-Kṛṣṇa ni otito to gaju, purusa ati prakrti. sugbon Rādhārāṇī lon sise. Rādhārāṇī si mo ise se tojepe, Krsna si ni ifarasi nitorri ise ton se. Ipo Rādhārāṇī niyen. Madana-Mohana ni oruko Krsna. Nibi ni ilu Vrndavana, Madana-Mohana wa, sugbon Madana-Mohana-Mohini ni oruko Rādhārāṇī. Krsna si lewa gan... orisa ife le mu wa l'okan, sugbon Orisa ife yi sini ifarasi Krsna. Nitorina ni oruko re seje Madana-Mohana. Radharani si l'agbara tojepe oun lon gba aya Krsna. Nitorina oun lo lagbara ju. Ni Vrndavana, nitorina ni awon eyan se feran lati p'oruko Rādhārāṇī, ju oruko Krsna lo- " Jaya Rahde." Beeni. Teba ore-ofe Krsna, egbiyanju lati jeki inu Radharani dun. Gege boseje niyen.

Nisin wanti so nibi, mana madana-vepitam: " Idamu wa ninuokan re." Idamu ninu okan yi ma lo titi afi teyan ba ni ifarafun Madana Mohana. Tawa o ba ni ifarasi Madana Mohana, tawa o ba nife fun Madana-Mohana agbudo nife fun Madana, madana-vepitam. Ilana to wa niyen. afi teba ni idari lori okan yin, lehin na Madana o le ni idari lori okan yin, kosejo ominiran tabi igbala. Ipinnu aye yi ni basele bo lowo awon idimu aye yi, iyika ibimo, iku ati awon isoro meta. Pipe aye yi niyen. Awon eyan yi o mo nkan ti ipinnu aye yi je, kini ipinnu ile aye yi, gbogbo agbaye. Nipataki ninu asiko tawayi, awon eyan ti wo lule tojepe, kosi bonsele mo ipinnu aye yi. gbogbo awon oni selu., awon alakowe, awon oni sayensi, kosi imoye kankan nini wan. wan wa ninu okunkun. Nitorina lonse pe ni itanraeni, ninu okunkun. sugbon o gbudo yewa pe Krsna surya sama: " Gege bi Orun ni Krsna seje."

kṛṣṇa sūrya-sama; māyā andhakāra
yāhāṅ kṛṣṇa, tāhāṅ nāhi māyāra adhikāra
(CC Madhya 22.31)

Mām eva ye prapadyante māyām etāṁ taranti te (BG 7.14). Ilana to wa niyen.

Sayensi to ga gan. Egbe imoye Krsna ni egbe tole yo gbogbo agbaye kuro ninu iho okunkun pelu awon ilana to daju gege bi sayensi.