YO/Prabhupada 0193 - Gege bi gbogbo awon eyan ninu awujo wa lon keeko lati awon iwe yi



Room Conversation with Professor Durckheim German Spiritual Writer -- June 19, 1974, Germany

Dokita P.J. Saher: Edakun sele salaaye si lori oro.. teyan ba korin Oruko Olorun, edakun sele salaaye leyokan si nkan to ma ..... ( Ede German) Kiloye ko se si , tabi bawo loseje, ninu awon eko teyin fun wa?

Prabhupada: Beeni. Nkan ton pe ni Bhakti-marga niyen, nkan t'alakoko ni sravanam, igboran. gege base ko awon iwe wanyi ati fun awon eyan l'aye ati le gbo nipa wan. Ise t'alakoko wa niyen. Tawa o ba gbo nipa olorun, awa kon ma fori ro awon nkan. Rara. Agbudo gbo nipa Olorun. Awa ti tejade iwe ọgọrin, e gbo nipa olorun. Teyin ba ti gbo dada ele salaye fun awon elomi. Nkan ton pe ni kirtanam. Śravaṇam, kīrtanam. teba si tesiwaju pelu ilani yi,pe eyin korin ten salaaye, ijuwe nitumo kirtanam. Gege bi awujo wa, gbogbo wan lon gbo nipa awon iwe yi, wan sin jade lati salaaye fun awon Nkan ton pe ni kirtanam niyen. Lehin na pelu awon ilana mejeji wanyi, igboran ati orin kikp, ema ranti, smaranam. Itumo re niwipe ema ranti, egbudo ni asepo pelu Olorun.

Dokita. P. J Saher: Nigbogbo igba, " Eranti mi."

Prabhupada: Beeni. Beeni. Śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ smaraṇaṁ pāda-sevanam (SB 7.5.23). tesi s'adura si awon irisi Olorun, te s'adura pelu ododo si ese Olorun, ati aso, pāda-sevanam, arcanaṁ vandanam, te s'adura, dasyam, te sise. gege bayi, ilana mesan lowa.

Dokita. P. J. Saher: Awa sini nkan to jo ninu esin Kristiani, (Ede Germani).

Prabhupada: Beeni. Ilana Kristiani, adura. bhakti leleyi je. Bhakti leleyi. (Ede Germani) Ija nitumo Kali-yuga. Koseni to fe mo nipa otito, sugbon wan fe ja. " Nkan temi ro niwipe", Oun na asowipe " Nkan tooun ro niwipe." Orisirisi ipinnu, lehin na wan bere sini ja laarin ara wan. Asiko tawa niyen. Kosi ipinnu kan to daju. Gbogbo eyan loni ipinnu t'ara re. Nitorin awon eyan gbudo ja. Gbogbo a sowipe, " Bi mon sen ronu leleyi." kini iwulo re,, teyin sen ronu bayi? kali yuga niyen. Nitoripe eyin o ni imoye kankan to daju. T'omode ba sofun baba re, " Mo rope oyeko se bayi". Soyeka gba iru ipinnu yi? Teni ni o ba moni pa nkan na bawo losele fun wa ni ipinnu kankan? Sugbon nisin, lasiko tawayi, gbogbo eyan loni ipinnu tie. Nitorn ni awon eyan sen ja. Gege bi awon apapọ orilẹ-ède, gbogbo awon eyan pataki lon losibe lati le ni asepo sugbon gbogbo wan lon ja lati ni ilu tiwan. Otan Ogun. Awujo ija nikan. Awon Pakistan, awon Hindustan, awon orile-ede America, awon Vietnam. Fun alafia wan daale sugbon ibasepo ija loti di nisin. Otan Gbogbo nkan. Nitoripe koseni kankan to mo nkankan,gbogbo eyan n'soro.

Obirin omo-ilu Germani: Se iyen wipe gbogbo igba ni Kali yuga yi wa?

Prabhupada: Rara. Asiko ti awon alalogbon lori ti jade (isinmi)... dipo ton ma wa ona abato si, wan jagun si. Nitoripe kosi'po kankan to daju. Nitorina Brahma-sutra sowipe egbudo gbiyanju lati sewaadi nipa otitio to gaju. Athāto brahma jijñāsā. Nisin idaaun, Lati Brahman, tabi otito to gaju nigbogbo nkan ti wa. Athāto brahma jijñāsā, janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). Nisin eti ri ibi ti.. gbogbo eyan lon wa orisun gbogbo nkan aye yi. Ipinnu toye ka tele niyen. Pe teba tele awon oro wanyi gbogbo ija yin ija yin tan. Ori yin ma pe wa. Ese-iwe yi Tattva jijñāsā. Lati se waadi lori otitoto gaju nitumo Tattva jijñāsā. E joko, nitoripe awon ipo okurin to l'ogbon gan gbudo wa ninu awujo awon eyan, ton soro nipa otito to gaju ti, lehin na awon na ma salaaye fun elomi. "Otito to gau leleyi, ore mi .." Ese bayi. Nkan ta fe leleyi. Sugbon nisin gbogbo eyan loti si otito to gaju. Nitorina lon sen ja.