YO/Prabhupada 0196 - Igbekele ohun nkan mimo



Lecture on BG 2.58-59 -- New York, April 27, 1966

Agbudo ko basele ri bi aye mimo se lewa to. Lehin na, ale fi awon nkan aye yi sile. Gege bi awon omode, okurin. Nigbogbo igba lon fajogbon, sugbon teba fun nise to da... Awon ile-eko ti wa orisirisi ona, bi ile-ẹkọ jẹle-osinmi, tabi awon ilana orisirisi. Sugbon tonba fun ni nkan se, ton ko Abidi." Gege na ale ko Abidi, sugbon lowo kan na koni le fa jogbon mo. gege na, ninu ile aye mimo oni awon nkan toda bi ile-ẹkọ jẹle-osinmi tawa ba sise ninu awon ise mimo wanyi, lehin na lale l'agbara lati fiawon nkan aye yi sile. Kosi basele se ka ma sise. Kosi basele se ka ma sise. Gege bi apeere ti Arjuna... Koto gbo oro Bhagavad-hita, kofe se nkankan, kofe jagun. Sugbon lehin igba to gbo Bhagavad-gita yi tan, o bere sini sise. Gege na kon sepe teyan ba ya si ile aye mimo, koni sise mo. Eke niyen je, tab kon joko, " Oh, mio ni sise ile aye yi mo. Mofe se iṣaro le Olorun, Oh, iru iṣaro woo lofese? Gbogbo iṣaro tonse ma paari lese kan gege bi Viśvāmitra Muni, tio le paari isaro ton se. Agbudo sise nigbogbo igba ninu awon ise mimo. Bi ilana ile-aye wa yeko ri niyen. Ninu aye mimo eyin gan o le ri asiko kankan lati jade kuro. Ise tani lati se po gan. Rasa-varjam. Sugbon ise a rorun lati se tawa bari idunnu ninu ise na.

Nkan toye ka se niyen. Nkan toye ka se niyen. Ādau śraddhā tataḥ sādhu-saṅgaḥ (CC Madhya 23.14-15). T'awa ba ti ya si aye mimo, nkan alakoko ni, śraddhā, igbagbo. gege bi eyin sen wa sibi lati gbo nkan timon so. Eyin tini igbagbo die. Ibere niyen. Lasi igbagbo, eyin o ni wa sibi nitoripe lasiko yi ele lo si awon ile-sinima, awon soro lori awon eto iselu,... Awon eyan imi le ro wipe, awon eto to gbe lasan la wan so (erin) Sugbon kilode tese wa? Nitoripe eyin sini igbagbo die, "Oh, Bhagavad-gita leleyi. ejeka gbo. Igbagbo ti bere niyen. Awon alainigbagbo kosi bonsele ni ile aye mimo. Igbagbo ni bere. Ādau śraddhā. Śraddhā. Sugbon igbagbo yi, teba si jeko dagbasi, eleni ilosiwaju. Agbudo jeki igbagbo yi dagbasoke. Ibere igbagbo wa niyen. nisin ti'gbagbo yin ba dagbasoke, eleni ilosiwaju laano ile aye mimo. Ādau śraddhā tataḥ sādhu-saṅgaḥ (CC Madhya 23.14-15). Teba ni'gbagbo, ema ri awon sadhu, sadhu tabi awon alufaa, tole fun yin imole ninu awon eto emi. Nkan tonpe ni sadhu-sanga niyen (CC Madhya 22.83). Ādau śraddhā. śraddhā ni ilana t'alakoko, sādhu-saṅga ni ipo to tele, ibasepo pelu awon eyan tonti ni ilosiwaju ninu eto mimo. Nkan ton pe ni sādhu... Ādau śraddhā tataḥ sādhu-saṅgo 'tha bhajana-kriyā. ti eba ni ibasepo pelu awon eyan wanyi tonni imo nipa eto emi, lehin na eyan bayi le fun yi ni ilana eto mimo. Nkan ton pe ni bhajana-kriya. Ādau śraddhā tataḥ sādhu-saṅgaḥ atha bhajana-kriyā tataḥ anartha-nivṛttiḥ syāt. teba se sise si ninu awon eto emi, gege na awon ife yin si awon nkan aye yi ma dinku. Idapada. Teba sise ninu awon eto emi, ifarafun sinu awon aye yi ma dikun. Sugbon efoju si. Ise ike-aye yi ati ise mimo, iyasoto to wa niwipe.. Kasowipe eyin sise bi okurin iwosan. Eyin o rowipe " Tin ba bere sini sise ninu awon eto emi, lehin na ma fi ise mi sile." Rara, rara. Bose ri koniyen. Egbudo ya ise yin si momi. gege bi Arjuna, ologun loje. Sugbon o si di okurin mimo. gege na o ya ise ogun jija re si mimo.

Awon ilan to wa niyen. Gege na ādau śraddhā tataḥ sādhu-saṅgaḥ atha bhajana-kriyā tataḥ anartha-nivṛttiḥ syāt (CC Madhya 23.14-15). Itumo Anartha ni... Nkan ton funwa ni isoro nitumo Anartha. Awon ise ile aye yi ba funmi ni ibanuje. teba si yi ile aye yin si mimo, lehin na awon isoro aye yin ma dinku, die die wan tan. lehin na taba ti bo lowo gbogbo awon nkan aye yi, ile aye mimo yin ma bere. Athāsakti. Eti ni ifarasi. Kosi besel fi sile. Nigbati awon anartha-nivṛtti yin ba tan, nigbati awon ise ile aye yin ba tan, lehin na kosi besele fi sile. Athāsakti. Ādau śraddhā tataḥ sādhu-saṅgo 'tha bhajana-kriyā tato 'nartha-nivṛttiḥ syāt tato niṣṭhā (CC Madhya 23.14-15). T igbagbo yin ba ti le gan itumo Nistha niyen, Tato niṣṭhā tato ruciḥ. Ruci. Itumo Ruci niwipe ema bere sini wa awon nkan mimo. Eyn o ni fe gbo awon nkan tio ni oro mim ninu e. Eyin o ni feran awon nkan tio ni asepo pelu nkan mimo. Eyin o ni fe je ounje tio ni asepo pelu awon nkan mimo. gege na ile aye yin ma yipada. Tato niṣṭhā athāsaktiḥ. lehin na ifarasi, lehin na bhava. Lehin na ema ni idunnu to po repete. Idunnu yi ma wa. Orisirisi ipo lowa lori awon ipo aye mimo to ga. Tato bhāvaḥ. Tato bhāvaḥ. Bhāva, ipo bhāva, yi ni'po latibi tele ba Olorun soro fun ara re.