YO/Prabhupada 0199 - Awon asiwere wanyi ton s'asoye iranu, wanfe yo Krishna kuro



Lecture on BG 13.8-12 -- Bombay, September 30, 1973

Igbagbo laisi imoye , oro itara loje. sugon imoye laisi apa esin ninu e, ejo isokuso niyen. Awon meji yi n'sele nigbogbo agbaye. Orisirisi awon esin wa , sugbon koseyi toni imoye kankan. Nitorina ni awon esin aye isin o se le fun awon eyan ni idunnu kankan. Wanti ti fi gbogbo awon esin yi s'egbe kan, kristiani, tabi musulman, tabi Hindu. wan ko daabi ebo, awon eyan osi fe iru nkan bayi. Wanfe mo gbogbo nkan lori ipo imoye. Bhagavad-gita niyen.

Lori imoye ni Bhagavad-gita wa, ilana to wa niyen, Krsna-bhakti. Krsna-bhakti nitumo Bhagavad-gita, ifarasi krsna, imoye Krsna. Bhagavad-gita niyen. Bhagavad-gītā, eko re ni: man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). Bhagavad-gita niyen. " E ronu mi nigba gbogbo." Keni imoye Krsna, ke yasi mimo ati wipe ke rorun. Man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). Krsna ti salaaye nibikibi lori iru eyan toje. Aham ādir hi devānām: (BG 10.2) "Emi ni orisun gbogbo awon devata." Mattaḥ parataraṁ nānyat kiñcid asti dhanañjaya (BG 7.7).

ahaṁ sarvasya prabhavo
mattaḥ sarvaṁ pravartate
iti matvā bhajante māṁ
budhā bhāva-samanvitāḥ
(BG 10.8)

Gbogbo nkan lo wanbe. gege na sarva dharmān parityajya mām ekam (BG 18.66), mām, aham, emi." ninu gbogbo esw-iwe ati apa-iwe, Krsna. Mayy āsakta-manaḥ pārtha yogaṁ yuñjan mad-āśrayaḥ. Mayy āsakta, " Eyan to feran mi," āsakta-manaḥ," toti gbokan le mi, yoga niyen." Yogīnām api sarveṣāṁ mad-gatenāntarātmanā. Mad-gata, again mat (BG 6.47). Mad-gatenāntarātmanā, śraddhāvān bhajate yo māṁ sa me yuktatamo mataḥ. Gbogbo ejo yi sin salaaye nipa Krsna, sugbon awon asiwere wanyi ton s'asoye lori iwe na fe yo Krsna kuro.

Iru iwa were yi ti da wahala sile ni orile-ede India. Awon asiwere wanyi ton s'asoye iranu, wanfe yo Krsna kuro. Nitorina ni egbe imoye Krsna yo se jade lati fun awon were yi ni ipenija. Awa fe sofun wan wipe " Efe soro Krsna laisi Krsna ninu e. Iranu niyen."