YO/Prabhupada 0205 - Ko dami loju pe awon eyan ma gba



Morning Walk -- May 20, 1975, Melbourne

Prabhupāda: Kon se pe E gbudo ri pe eyan na ti ni igbabo ninu esin wa, nitoripe ko rọrun rara ati ni igbagbo ninu iwaasu ti awa. Ko rọrun rara. Aimoye aduru aye to ma gba lati ni igbagbo na bahūnāṁ janmanām ante (BG 7.19) Sugbon egudo ma se ise yin lo. Elọ ke si waasu fun wan. Yāre dekha, tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa (CC Madhya 7.128). Lehin na ise yin ti tan. O daju na pe ema gbiyanju lati se iyipada nini okan wan. sugbon ti eyan na O ba ni iyipada ninu okan re, ìwòsọ́tùúnsósì yi o kin se ise yin. Ti yin ni pe ke ti waasu fun wan. Gege be emi na, nigbati mo de si Orile-ede yin ko da mi loju pe mo le ni aseyori ninu iwaasu ti mo mu wa. Nitoripe o dmi loju pe won ma sa lo lesekese ti mo ba wi pe " ema je eran mo, tabi ema si se Ibalopo afi teba ti se igbeyawo" Nitorina ko damiloju pe mo le ni aseyori bayi.

akeko (1): Won ti baramo

Prabhupāda: Beeni. Sugbon nitoripe e ni aanu fun mi lo je ke gba so kan iwaasu ti mo mu wa. O jo mi loju gan Mi o ro rara pe awon eyan ni Orile-ede yin ma gba iwaasu mi s'okan. Mi o ro rara.

Hari-śauri: Bee na, taba gbokan le Kṛṣṇa....

Prabhupāda: Beeni, ise tani se niyen.

Hari-śauri: taba si gbokan le abajade to ye...

Prabhupāda: Awa o ni nkan mi lati se ju pe ka se ise wa gege bi Oluko wa se so. Guru-kṛṣṇa-kṛpāya (CC Madhya 19.151). Gege na, e ma ni iranlowo lati Oluko at Krsna (Oluwa) aṣeyọri ni ye je.