YO/Prabhupada 0208 - E gb'ààbò lowo eyan toje olufokansin ti Krishna



Lecture on SB 6.1.16 -- Denver, June 29, 1975

Eyan to ba je Vaiṣṇava ko si le se ese mo, ohunkohun to ma ti se tele na ti tan. Bayi ni Kṛṣṇa (Oluwa) ti wi Ka si so wi pe ti eyan ba tin se ise Oluwa won ti bo lowo gbogbo ese ton ti se.

Bawo ni eleyi se je? Yathā kṛṣṇārpita-prāṇaḥ. Prāṇaḥ, prāṇair arthair dhiyā vācā. Prāṇa, aye ni itumo prāṇa Awon eyan ti won ti fun igbese aye won fun ise Oluwa Bawo la sele fi igbese aye wa fun ise Oluwa? Iwe mimo na si so wi pe: tat-puruṣa-niṣevayā. Agbudo tele awon oluse Oluwa. Itumu iyen ni wi pe agbudo gba Oluse Oluwa bi alaabo wa. Ninu iwe mimo Bhakti-rasāmṛta-sindhu, Rūpa Gosvāmī so wi pe ilana akọkọ, ādau gurvāśrayam ni wi pe agbudo gba sinu aye wa Oluse Oluwa bi Oluko, Itumu pe a gba Guru (Oluko) ni wi pe ati gba sinu aye wa aláṣojú Oluwa Eyan ti o ban se aláṣojú Oluwa ko le je guru. Kon se enikeni lo le di Guru, ogbudo je eyan to daju, tat-puruṣa. Itumu Tat-puruṣa ni eyan to ti gba Olorun bi ohun gbogbo Tat-puruṣa-niṣevayā. Itumu eyi ni Oluse Oluwa Ko de le. Pelu Ore-ofe Krsna (Oluwa) asi ni awon Oluse Oluwa ton le fun wa ni idaabobo. Ādau gurvāśrayam Itumo sad-dharma-pṛcchāt ni pe lehin igba ti eyan ba gba Oluko Eyan gbudo bi leere nipa sayensi Oluwa Sad-dharma-pṛcchāt sādhu-mārga-anugamanam. Imo Krsna (Oluwa) ti awan se itumo re ni wi pe agbudo se gege bi awon Oluse Oluwa, sādhu-mārga-anugamanam.

Gege na awon wo ni won pe ni sādhus?

svayambhūr nāradaḥ śambhuḥ
kumāraḥ kapilo manuḥ
prahlādo janako bhīṣmo
balir vaiyāsakir vayam
(SB 6.3.20)

Awon mejila eniyan ti won da oruko won, mahajana lon si pe won alaṣẹ ni awon eyan mejila won yi, agbudo tele won. Ko de le itumo Svayambhu ni Brahma. Svayambhūḥ nāradaḥ śambhuḥ. Itumo Śambhu ni Siva Ninu awon mahajana mejila won yi, merin se pataki Svayambhu itumu re je Brhama, Sambhuh, ati awon Kumarah Otun ni samradaya mi ti won pe ni Śrī sampradāya, eleyi wa lati Laksmiji. Gege na agbudo gba Oluko to bosi ikon ninu awon Ẹgbẹ merin Igba no la le ni aseyori Sugbon ta ba gba sinu aye wa Oluko to fe tan wa je, ko le se se. Agbudo gba ni Oluko eyan to wa ninu ikon ninu awon egbe merin Awon mimo si juwe fun wa pe tat-puruṣa-niṣevayā: O ye ka gbiyanju ati se ise fun pelu okan t'Olóòótọ Te ba de se gege ba se so, ke si fun Oluwa ni igbese aye yin, eredi aye ni yen je. E gbiyanju lati si ise fun Oluwa labe labẹ itọsọna tat-purusa Itumu e yi ni wipe awa o ni ise imi ju ti Oluwa lo. Nigbana awa o si bo lowo gbo gbo ese ta ti se. Nitoripe mimo ni Krsna (Oluwa) Arjuna so wipe, paraṁ brahma paraṁ brahma pavitraṁ paramaṁ bhavān Oluwa mi eyin ni eni eyan to ga julọ Afi taba di mimo eyan o le sumo Olorun gege bayi ni iwe mimo ti so. Ati won inu ina eyan gbudo di ina bakanna ti eyan o ba ya si mimo ko si le wo inu ile Olorun Gbogbo esin ninu aye yi si wi be Esin Kristiẹni si wi be na, pe lai di mimo eyan o le wo inu ile Olorun.