YO/Prabhupada 0211 - Basele tesiwaju pelu egbe Sri Caitanya Mahaprabhu ni iṣẹ apinfunni ti awa ni



Lecture on CC Adi-lila 1.4 -- Mayapur, March 28, 1975

Koseni to le fò ko ja imo-ohun Oluwa lai ni Ore-ofe Śrī Caitanya Mahāprabhu lati ni Ore-ofe Śrī Caitanya Mahāprabhu ani lati gba saye Ore-ofe awon Gosvāmīs mefa. Eto paramparā ni eyi je Nitorina Narottama dāsa Ṭhākura so wi pe

ei chay gosāi jār-tār mui dās
tā-sabāra pada-reṇu mora pañca-grās

Eto paramparā ni yen. Ko seni to le fo ko ja lai gba inu eteo paramparā Lati gba Ore-ofe awon Gosvami ani lati gba ti Oluko ni ala koko gege na lati gba ore-ofe Śrī Caitanya Mahāprabhu, agbudo ni Ore-ofe awon Gosvami gege na lati Śrī Caitanya Mahāprabhu a le tesiwaju si Krsna (Oluwa). Bo se je ni yen Nitorina Narottama dāsa Ṭhākura so wi pe ei chay gosāi jār-tār mui dās iranṣẹ ti awọn iranṣẹ ni gbogbo wa je itọsọna ti Caitanya Mahāprabhu fun wa ni wi pe gopī-bhartuḥ pada-kamalayor dāsa-dāsānudāsaḥ (CC Madhya 13.80). be ba se rẹ̀ sílẹ̀ to gege be na le ma se ni itesiwaju sugbon ti eba fe di Oga, ọrun-apaadi le ma ba ara yin. E maṣe ṣe bayi mo, ikẹkọ Śrī Caitanya Mahāprabhu ni eyi je te ba si gba ni Oga awon iranse, ti awon oranse diẹ diẹ eyin na ma di Oga Sugbon te ba bere si ma ronu pe eyin na ti di Oga, e ma lo si Orun apaadi ilana ni eyi je. Caitanya Mahāprabhu so wi pe Dāsa-dāsānudāsaḥ. Iranse ni ona igba ọgọrun, itumo yen ni wi pe Eyan na ti ni ilọsiwaju. Sugbon enikeni to ba di Oga lai di Iranse , Orun apaadi lo ma ba ara re.

Gege na anarpita-carīṁ cirāt Agbudo ranti itọnisọna ti Śrīla Rūpa Gosvāmī nigbagbogbo Nitorina awan man gbaadura: ṣrī-caitanya-mano-'bhīṣṭaṁ sthāpitaṁ yena bhū-tale. ètò àgbékalẹ̀ tawa ni lati ṣedasilẹ ohun ti Śrī Caitanya Mahāprabhu ba fe. ise wa ni yen. Śrī-caitanya-mano-'bhīṣṭaṁ sthāpitaṁ yena bhū-tale. Śrīla Rūpa Gosvāmī ti se ise yi fun wa. O ko awon iwe to po gan. nipataki iwe Bhakti-rasāmṛta-sindhu, ta ti fi itumo sinu èdè gẹ̀ẹ́sì pelu oruko " Nectar of Deovotion" lati se iranlowo fun awon ton ba fe ni oye eto ise ifarafun t'Oluwa ilowosi pataki ti Śrīla Rūpa Gosvāmī se ni wi pe, O ko wa ba se le di iranse Oluwa Eto bi a se le di iranse oluwa kon se nkan a fi sere, sayensi lo je. sayensi nla ni egbe imo-ohun Krsna (Oluwa) Yad vijñāna-samanvitam. Jñānaṁ me paramaṁ guhyaṁ yad vijñāna-samanvitam. Kon se nkan a fi sere Te ba mu bi nkan a fi sere, ema da idilọwọ si le. gege na ni itọsọna Rūpa Gosvāmī. O so wi pe,

śruti-smṛti-purāṇādi-
pañcarātriki-vidhiṁ vinā
aikāntikī harer bhaktir
utpātāyaiva kalpate
(Brs. 1.2.101)