YO/Prabhupada 0222 - Ema gbowole ninu eto lati fun egbe wa ni ilosiwaju



His Divine Grace Srila Bhaktisiddhanta Sarasvati Gosvami Prabhupada's Disappearance Day, Lecture -- Los Angeles, December 9, 1968

Egbe wa si da gan Ahaṁ tvaṁ sarva-pāpebhyo mokṣayiṣyāmi mā śucaḥ (BG 18.66). Ninu iwe mimo Bhagavad-gītā, Oluwa so wi pe awon eyan ni inira to po nitori ese ton ti se aimọ. Idi awon ese ni aimo opolopo awon eyan E je k agba wi pe eyan to wa sinu oridle-ede America pe ajeji lo je, ko de mo... Gege na ni ilu yin awon man wa oko ni apa otun, Ni Orile-ede India gege bi Orile-ede London mo si ti ri pe awon eyan man wa oko wan ni apa osin e gba wi pe eni to wa ko mo, o si wa oko re ni apa osin, àdébá lo ma daale sugbon Olopa si wa mu to ba so wi pe " e ma binu , mi o mo pe ni Orile-ede yin apa otun le man wa oko yin" Se ro boya Olopa ma fii le. Ijoba a si fiyajẹ ẹlẹṣẹ Gege na aimo ni idi ti awon eyan fi se isekuse sugbon te ba ti se isekuse yen tan e gbudo jiya fun Gbogbo aye si wa ninu okunkun, nitori okunkun yi orisirisi nkan lo ti sele Ko si nkan to da ninu aye ta wa yi, opolopo nkan aye yi buru a ti da si le, awon nkan to da ati awon nkan to buru nitoripe ninu iwe mimo Bhagavad-gītā o ti ye wa pe ile-aye yi duḥkhālayam aśāśvatam (BG 8.15) Ibanuje ni ile aye. bawo l'eyan se le so wipe Eleyi da tabi Eleyi buru ninu ile aye yi. Gbogbo nkan lo buru gege na awon eyan ti o mo itumo aye yi wa si da nkan mi sile Eleyi da, tabi Eleyi buru, nitoripe wan o o pe gbogbo nkan aye yi lo buru ti eyan ba fe pa da s'Orun ogbudo ma ni'fe ile aye yi Duḥkhālayam aśāśvatam (BG 8.15). Ile aye afi ibanuje nikan, teba de wo daada, eyin na ma ri be Nitorina agbudo fi ile aye si le, ka yipo si aye mimo ni imoye Krsna (Olorun), awan sin gbiyanju lati le di mimo lehin na a le pa da si ijoba Orun. yad gatvā na nivartante tad dhāmaṁ paramaṁ mama (BG 15.6), Ijoba na, a ba si de be ko soro pe apada. Ijoba Olorun ni yen.

Iwe mimo Bhagavad-gītā si juwe ibe fun wa Egbe imoye Oluwa yi oo se pataki gan Eyin Okurin ati Obirin Orile-ede America te ti gba egbe s'okan esi mu ni pataki iṣẹ apinfunni ti Oluko temi ati Oluwa Caitanya sugbon awan sin gbiyanju lati le da egbe yi Gbogbo yin si ti wa ranmi lowo, Mo si le ku, sugbon eyin si ma wa ema si gbowo si le l'eto itesiwaju egbe wa, Olwa Caitanya asi fun ni ibukun gege na Bhaktisiddhānta Sarasvatī Goswami Prabhupāda.

Ese pupo.