YO/Prabhupada 0225 - E ma se ni ibanuje , E ma se ni idamu



Lecture at Engagement -- Columbus, may 19, 1969

Igbese aye yi wa fun imora eni. tani mi, gege na asi wuwa bo se ye Gege na Bhāgavata so wi pe, ti awa o ba le de ipo ta le mo ara wa, nitorina ohunkohun ti eyan ban se, isekuse lo je, tabi ilokulo asiko lori na, wan si kiloo fun wa pe ka ma lo aye wa ni ilokulo Ejo a gbiyanju lati mo iwe mimo Veda O ni oloselu kan tan pe ni Cāṇakya Paṇḍita alakoso ijọba ni ile aṣofin lo je si Oloye Candragupta, gege bi alagbara Alexander lati Orile-ede Greece gege bi alakoso ijọba ni ile aṣofin, O si da awon ofin mimo fun awon eyan Ni kan ninu awan ẹsẹ-iwe re o wi pe āyuṣaḥ kṣaṇa eko 'pi na labhyaḥ svarṇa-koṭibhiḥ. Āyuṣaḥ, "iwonba aye yin", ka sowipe omo odun ogun le je Ojo Ọkandinlogun osu karun leni je, ago kerin si ni. gege na ago kerin, Ojo kandinlogun ni Osun Karun ni odun 1969 ti koja. Ko si be se le ri pada, ton ba tie fun yin ni owo repete. ko lesese gege na, asiko die ninu aye yin te ba lo niilokulo, pe eyin gbadun tiyen jeun, tieyin mu, t'en sun, t'en se asepo t'oko ti yawo, ko si be sele mo amuye aye yi ko si aduro owo tele fi ra asiko to ba koja ninu aye yin E gbiyanju lati mo bi ile-aye yin se dara to.

Gege na anfaani egbe yi ni lati ko awon eyan bi igbese aye wan se daara to Itumu egbe wa ni sarve sukhino bhavantu: ki inu gbogbo eyan dun ko den se awon eyan nikan, gege na awon eranko gan. A fe ki inu gbogbo eyan dun Egbe Krsna wa ni yen. O de se se. Kon se ala. INu eyin le dun si Ema si ni ibanuje, tabi idààmú. Ile aye yin niyi gan ni aye te wa yi, ele mo nipa aye ti o l'opin O rorun, ko de le awan si gbiyaju lati fun gbogbo araye ni iwaasu yi Aye yin dara, ema si loniilokulo bi awan aja ati Ologbo. E si lo tan Asewi iwe mimo hagavad-gita niyen Asi ti ko iwe mimo Bhagavad-gita, E gbiyanju ke si ka iwe na Ni Bhagavad-gita ipin kẹrin, o si so wi pe, janma karma ca me divyaṁ yo jānāti tattvataḥ: ki eyan gbiyanju lati mo Olorun Krsna ati awon nkan to se Kini aye re, Ibo lon gbe, kini ise ton .. janma karma itumo janma ni ifarahan ati ipaarẹ, itumo karma ni ise, itumo divyam- mimo Janma karma me divyaṁ yo jānāti tattvataḥ. Enikeni to ba mo awon ise mi ati ifarahan mi, oun lo mo ni ooto. Kon se oro pe aronu, sugbon oro ipo ati sayensi, esi ni wi pe tyaktvā dehaṁ punar janma naiti mām eti kaunteya (BG 4.9). Ti oro Krsna ba ye yin, ko ni si stunwa si ile aye yi mo fun yin Oto oro ni eyi je. Gege ninu aye yin inu yin ma dun.