YO/Prabhupada 0229 - Mofe ki ikan ninu awon akeko temi koni oye nipa imoye Krishna



Conversation with Indian Guests -- April 12, 1975, Hyderabad

Prabhupāda: isoro to wa ni wi pe ko seni to fe di akeko wan ko die ni bi, die nloun, sugbon nkankanna ni wan sayensi lo je. Iwe Veda so wi pe tad vijñānārthaṁ sa gurum evābhigacchet (MU 1.2.12). to ba se pataki funn yin lati ko eko tad vijñāna. Tad vijñānaṁ, gurum evābhigacchet. egbudo lo si odo Oluko to laari, to le ko yin Opolop awo eyan o daju. Isoro to wa ni yen Gboeyan ronu pe, " mo le se bo se wunmi", sugbon ayanmọ asi fa leti. Prakṛteḥ kriyamāṇāni guṇaiḥ karmāṇi sarvaśaḥ (BG 3.27). Oti se bayi, bo sibi ko joko. Nka ti prakṛti se fun wa ni yen Ahaṅkāra-vimūḍhātmā kartāham iti manyate (BG 3.27). awon asiwere wan ronu pe " emi l'Oga, mo si le se bo se wunmi" Awon eyan ton ronu bayi, iwe mimo Bhagavad-gītā ti s'alaaye bon se je, ahaṅkāra vimūḍhātmā. Ogbon ori wan si ti yipo, wan de ronu pe " Gbogbo nkan ti mon ro lo da" Rara, E le ronu be se fe. Egbudo ronu bi Krsna se fe nigbana le ma ronu dada bibeko, ekon ma ronu sodi Tribhir guṇamāyāir bhavair mohita, nā 'bhijānāti mām ebhyaḥ param avyayam. Mayādhyakṣeṇa prakṛti sūyate sa-carācaram (BG 9.10). awon nkan yi si wa E ka iwe mimo Bhagavad-gītā, e tele awon ofin ninu re, igbese aye yin a si da sugbon te ba fe se bo se wunyin ema ronu sodi Ema sonu,Otan Nkan ti Krsna ba so lo da. Bibeko ema sonu awan sin gbiyanju ati se iwaasu gbogbo imoye yi a lee ma po, sugbon ekaś candras tamo hanti na cittara sahasra. Osupa kan tito lati fun wa ni ina, kini iwulo awon irawọ ilana wa ni yen, ti Enikan soso ba ni oye Krsna, iwaasu mi ti ni ilosiwaju ni yen Awa osi fe irawọ to po, ti o le tan na kini iwulo irawọ ti o ni ina? Ilana Cāṇakya Paṇḍita na ni yen, , varam eka putra na chavur kasatan api. Ti eyan ba ni omo kan to l'ogbon, iyen nan tito. Na chavur kasatan api kini iwulo awon omo to po repete,to ba je pe asiwere at'ode ni gbogbo wan? Ekaś candras tamo hanti na cittara sahasras. Osupa kan tito ati tan na Ko si iwulo fun irawo repete Gege na, awa o si fe awon akeko to po Mo fe ri akeko kan pere to ni oye imoye Krsna. Otan Krsna so wipe yatatām api siddhānāṁ (BG 7.3), kaścid vetti māṁ tattvataḥ. sugbon ati di siddha ko si rorun rara lehin na yatatām api siddhānām (BG 7.3). ise to le gan ni eyi je. Gege na Iwaasu Krsna o soro ati ni imoye re to ba rorun fun wan lati mo, oye gidi ko niye je te ba gba ilana Krsna O rorun gan. Ibo ni isoro wa? krsna so wipe man-manā bhava mad-bhakta, mad-yājī māṁ namaskuru, always think of Me. Ki lo le nibe? Eti ri iworan Krsna, ki lo tun le? lehin na gbogbo wa,la man ronu. dipo te ma ronu nkan mi, kilo de ti eyin o le ronu Krsna? ki ni isoro to wa? sugbon ko ro pe o se pataki. O ni lati ronu nkan to po, sugbon ko fe ronu Krsna Krsna de so wipe, man-manā bhava mad-bhakta. Esin wa si rorun a ti tele. sugbon awon o si le tele. wan kan ma jiyan. Kūṭaka. Kṛṣṇa so wi pe, man-manā bhava mad-bhakta, ki lode ti eyin fi jiyan Eyin so wipe awon eyan o le ronu Krsna, wan le ma soro nipa Krsna Krsna de so wipe, man-manā bhava mad-bhakta. ariyanjiyan ni eyi je, kon se imoye. Ilana to ye ke tele si wa. Te ba se bo se so, ema ri esi na te ba fe ran nkan, wa so iye to je, teba ti san wo nkan te ra ti di tiyin. kilani ati jiyan? ti nkan ba se pataki fun yin, e ma san wo esi mu lo Ilana ti Śrīla Rūpa Gosvāmī fun wa ni yen. Kṛṣṇa-bhakti rasa-bhāvitā-mati kriyatāṁ yadi kuto 'pi labhyate teba le ran nkan fun Krsna, nkankana ni pelu eyan ton ronu krsna. kṛṣṇa-bhakti rasa-bhāvitā mati. gege na ati so ise yi si imoye Krsna Ti eyan ba le fowo ra imoye Krsna yi, ko sare ra. Kṛṣṇa-bhakti rasa-bhāvita-mati, kriyatām,E ra yadi kuto 'pi labhyate, ton ba le ta fun yin ti mo ba fe ra, kini iye ti mo le san? Tatra laulyam ekaṁ mūlam. Na janma-koṭibhiḥ labhyate. te ba fe mo iye to je, egudo níwára sugbon aye kon ooto lati ni íwára lati fun Krsna Kilode te fe Krsna? gege bi mo se so tele ti eyan ba ri Krsna, A yawere fun Krsna Eleyi ni esi na