YO/Prabhupada 0239 - Eyan gbudo ni iye-ara to daju lati ni oye Krishna



Lecture on BG 2.3 -- London, August 4, 1973

iru aanu bayi gege bi t'Arjuna Ni isin, ijoba na ti beere si ni s'aanu fun awon apaniyan, wan kin pa wan mo. Arjuna ni yen. hṛdaya-daurbalyam ni yen. Ise wa ko ni yen Eyan lati se ise ti awon Olori giga ti pin fun, lai loori wo. Iru aanu bayi , ailers okan lo je sugbon ko le ye awon eyan lasan Nitorina lati le ni oye Krsna, agbudo ni iye-ara to daju. iye-ara to daju itumo re o wi pe ke yo oju yin kuro? rara E gbudo yasi mimo. Tat-paratvena nirmalam (CC Madhya 19.170) Gege bi pe te ba ni aisan ninu oju yin, e ma fi ogun si to ba de ti tan, e ma le riran dada bakanna, ko si ba se le ni oye Krsna pelu iye-ara wonyi ti o muna Sevonmukhe hi jihvādau svayam eva sphuraty adaḥ (Brs. 1.2.234). Oruko krsna, amuye Krsna, etc ko si bo se leye awon eyan, lehina bawo la se le ni oye re? sevonmukhe hi jihvādau. jihvādau, e si bere lati ahọn. Egbudo ni ìdarí lori ahon Se ri oe nkan to yato ni, lati ni oye Krsna egbudo ni idari lori ahon bawo lo se je pe mo gbudo se idari fun ahon mi kin to le ni oye nipa Krsna? sugbon iwe sastra so wipe : sevonmukhe hi jihvādau. ahon ni itumo Jihvā gege ka to le ri Krsna, ise wa t'alakoko ni wi pe agbudo ni idari lori ahon wa Nitorina lawa o se kin je eran, tabi mu oti. nitoripe awa fe ni idari lori ahon wa Ota tinu tinu ni ahon wa je si wa awon asiwere yi man so wi pe " E je nkan to ba wu yin. Esin yin o ni nkankan lati se pelu nkan ten je" Sugbon iwe Veda so wipe, " Te ba fe ni oye Olorun egbudo ni idari lori ahon yin ase Veda ni yen Ti eyan o ba le ni idari lori ahon re, ko s le ni idari lori ikun re, gege na eyan o le ni idari lori ibalopo eto ara eniyan Rūpa Gosvāmī so wi pe

vāco-vegaṁ manaso krodha-vegam
jihvāvegam udaropastha-vegam
etān vegān yo viṣaheta dhīraḥ
sarvām apīmāṁ sa pṛthiviṁ sa śiṣyāt.
(NOI 1)

Ilan to fu wa ni yen. Enikeni tí ó kúnni lójú gbudo ni idari lori ahon re idari lori, okan, ibinu, ikun, ati ibalepo eto ara eniyan ti awon idari wonyi ba wa laye eyan, o daju pe eyan na le di aalufa O si le ni awon akeko ni gbogbo aye Ti eyan o ba le ni idari lori ahon re, ko si bo se le ni idari lori ibinnu Ti eyan o ba ni idari lori nkan to wa lokan re, bawo ni eyan na se le di aalufa? ko le se se Pṛthiviṁ sa śiṣyāt. Gosvami ni wan pe ir eyan bayi, tabi Oga iye-ara Eyan lati di Oga ni eto idari lori awon iye-ara.

jihva ni t'alakoko. Sevonmukhe hi jihvādau svayam eva sphuraty adaḥ (Brs . 1.2.234).. Seva. Eyan le fi ahon re fi se ise fun Oluwa. Bawo na? E korin Kare Krsna, e yin Oluwa logo Vācāṁsi vaikuṇṭha-guṇānuvarṇane. Oro siso ni itumo Vācāṁsi Ise ahon ni lati soro pelu ounje jije Egbudo fun ahon ni ise Oluwa. ke si yin Oluwa logo Ti eyan ba le se ibura pe, " mi o ni soro afi to ba je pe mo fe yin Oluwa logo" Idari ahon ni yen E ma fi ahon yin so isokuso Igbmi ta ba pe jo, isokuso la man so. Agbudofi opin si Ni isin mo ti fi ahon mi ninu ise Oluwa, mi o le so isokuso mo idari lori ahon ni yen mi o le je nkankan ti Oluwa o ti fi ibukun si. Idari ahon ni iyen je awon ilana-iṣe kekere ni wonyi. sugbon wan ni yi repete Inu krsna a si dun a de fi ara re hon Krsna o le ye yin, koseni to le ri Eyan si le p'ase fun Krsna. " bosi bi mo fe ri e" Ase ni yen je. Krsna koja eni ton gba ase lowo wa Nitprina Caitanya Mahāprabhu ti fun wa ni awon ilana aśliṣya vā pāda-ratāṁ pinastu māṁ marma-hatāṁ karotu vā adarśanam (CC Antya 20.47).