YO/Prabhupada 0244 - Imoye wa niwipe Olorun ni olori gbogbo nkan ninu aye yi



Lecture on BG 2.9 -- London, August 15, 1973

Ni ijokan ni ilu Paris, onirohin lati " Socialist Press" wa ba mi Mo si so fun pe " ẹkọ ọgbọn wa ni wi pe Olorun ni olori gbogbo nkan" Krsna so wipe bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ sarva-loka-maheśvaram (BG 5.29). Onigbadun ni mi, bhoktā. Onigbadun ni itumo bhoktā. bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ. gege bi ara wan sen se ise Gbogbo ara wan si ise fun igbadun wa, sugbon nibo ni igbadun an tin wa? Lati ikun loti bere. Eyaqn gbudo fi ounje sinu ikun taba ni agbara to ka, ounje na asi wo ara wa. Nigayen nika ni eyan le ni igbadun, bibeko kole se se Ti ounje na o ba le wo ara yin, gege bi emi, mo ti darugbo. Ko soro igbadun Lati ikun ni igbadun tin bere idagbasoke awon igi lati orísun re lat bere tin eyan ba fi omi to po si Nitorina pada-pa ni oruko awon igi yi Lati ese ni won tin mu omi, at'ori ko gege bi awa, lati Ori ni awan tin jeun. Orisiri isasoto lowa LAti enu ni awa tin jeun, sugon awon igi jeun ati ese Sugbon agbudo jeun. Āhāra-nidrā-bhaya-maithuna. Eyan gbudo jeun, ko ba lati enu tabi ese Sugbon Krsna le jeun lati ibikibi to ma fe O le fi ese, owo, oju tabi eti , jeun, ibikibi to ba fe Nitoripe Olorun lo je, ko si iyasot laarin ori, ese, oju tabi eti re Brahma-samhita si wi be.

aṅgāni yasya sakalendriya-vṛttimanti
paśyanti pānti kalayanti ciraṁ jaganti
ānanda-cinmaya-sadujjvala-vigrahasya
govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi
(Bs. 5.32)

Sugbon ni ara ti awa lati ikun ni igbadun ma bere gege bi awon igi ma ni idagbasoke lati risun wan janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1), Krsna ni orisun gbogbo nkan aye yi Lai ni imoye Krsna , lai mu inu krsna dun, inu tawa na o le dun Bo se ri niyen. Nitorina bawo ni eyan sele mu inu Krsna dun? Ti gbogbo wa ba di Omo Krsna, Inu Krsna ma dun si wa Gbogbo nkan aye yi ti krsna lo je. Oto oro ni yen Ni isin awan je prasadam, nitoripe Olori ni krsna je, bhokta, Onigbadun Eyan gbudo fun Krsna ni gbogbo nka to ba ni, lehin na ele gba iyuko bi prasadam. Inu yin ma dun Nkan ti Bhagavad-gita wi ni yen. Bhuñjate te tv aghaṁ pāpaṁ ye pacanty ātma-kāraṇāt: (BG 3.13) Awon ti wan se ounje fun ara wan, ẹṣẹ lasan niwan je Bhuñjate te tv aghaṁ pāpaṁ ye pacanty ātma... Yajñārthāt karmaṇo 'nyatra loko' yaṁ karma... Egbudo se gbogbo nkan fun Krsna, pelu Ounje yin ga... Ele gbadun be se fe, sugbon lehin igbati ti Krsna ti gbadun tan Nigbana ele jeun. Nitorin ni oruko Krsna se je Hṛṣīkeśa. Olori lo je Olori iye-ara. Ko si be eyan sele gbadun iye-ara re gege bi ranse, eyan to je iranse ko le gbadun gege bi alase ton se ounje, ko le jeun afi to ba paari To ba dan wo, wan si le kuru Oga re gbudo jeun na, lehin na gbogbo awon irans na le gbadun.