YO/Prabhupada 0246 - Gbogbo àmúyẹ to da wa lara Enikeni toba di elesin Krishna



Lecture on BG 2.9 -- London, August 15, 1973

Ninu ile-aye yiigbadun ni idi gbogbo nkan bi ife, awujo eyan, ore.. maithunādi, bere lati asepo laarin Okurin ati Obirin. Yan maithunādi gṛhamedhi-sukhaṁ hi tuccham. ti eyan ba setan pelu maithunādi-sukham, oti gba ominira eyan ti di svāmī, gosvāmī. ti eyan ba ni ife asepo laarin okurin ati obirin, maithunādi, ko le di svāmī, gosvāmī. itumo Svami ni eyan toti di Olori iye-ara re gege bi Krsna se je Olori iye-ara, ti eyan ba ni imoye Krsna oun na a di olori iye-ara Kon se pe agbudo fi ipaari si iye-ara wa, Rara. Eyan gbudo ni idari lori e. " ti mo ba ni iwulo fun, mo ma lo, bibeko rara. Olori iye-ara ni yen Mi o gbudo huwa bi eyan ti o ni idari lori ara re.. awon iye-ara mi gbudo sise gege bi mo se so.

Nitorina oruko imi fun Arjuna ni Guḍākeśa. Olori ni oun na.. ojo ko lo je, alaanu ni Arjuna nitoripe elesin lo je Enikeni to ba di elesin Olorun ani gbogbo iwa to da Yasyāsti bhaktir bhagavaty akiñcanā sarvair guṇais tatra samāsate surāḥ (SB 5.18.12). Gbogbo iwa to dara bibeko bawo lo se je wi pe Ore tinu lo je si Krsna, ti o ba je pe nkankanna ni wan? irẹpọ laarin awon ore ma lagbara to ba je pe awon Ore na wa lori ipo kanna iye Odun kanna, akeko kanna, iwa kanna,.. bi ipo aye wan se jora si, bayi ni irẹpọ wan asi lagbara si Gege na ipo kanna ni Arjuna ati Krsna jo wa gege bi eyan to di ore pelu Olori ilu, tabi Oba, Okurin lasan ko lo je. Ipo kanna loni pelu Oba gege bi awon Gosvami, wan si fi ebi wan sile Śrīnivāsa Ācārya si saalaye, tyaktvā tūrṇam aśeṣa-maṇḍala-pati-śreṇiṁ sadā tucchavat. Maṇḍala-pati, awon Olori to gaju Awon Olori to gaju. alákòóso lo si je Ko le si irepo laarin awon eyan ti o ni ipo kanna Rupa Gosvami si fi awon bayi sile lesekese ti Rūpa Gosvāmī ati Sanātana Gosvāmī se imora pelu Śrī Caitanya Mahāprabhu wan si pinnu pe awon ni se ise ijoba mo, wan si tele Śrī Caitanya Mahāprabhu lati le ranlowo lati di ranse re, nitoripe koseni to le fun Śrī Caitanya Mahāprabhu ni iranlowo Sugbon taba gbiyanju lati di iranse re Ile-aye wa a ni ilosiwaju gege bi Krsna to wa fun wa ni iwaasu Bhagavad-gītā Sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ (BG 18.66). Eleyi ni iṣẹ apinfunni to wa se awon asiwere wanyi ti di iranse fun orisirisi nkan Awujo eyan, irepo, ife, esin, orisirisi nkan Awon Asiwere wanyi gbudo fi ipaari si gbogbo iranu wanyi Sarva-dharmān parityajya BG 18.66: E fi gbogbo iranu yi sile, e teriba funmi Esin leleyi je Bibeko, kilode ti Krsna se so wipe efi orisirisi esin ten se sile? O wa - dharma-saṁsthāpanārthāya O wa lati se atunse awon ofin ninu esin Ni isin O so fun wa pe, " E fi gbogbo e sile" itumo eleyi ni wi pe, Ounkooun ti ba ni imoye Oluwa, iyanjẹ ni esin na je Esin ko lan je. Itumo Esin ni dharmāṁ tu sākṣat bhagavat-praṇītam, Ase Olorun ni Ti awa o ba mo eni ti Olorun je Bawo lasele ni esin ti awa o ba mo nkan ti aase re je? wan le so wi pe Esin ni wan sin, sugbon iyanje ni gbogbo e.