YO/Prabhupada 0247 - Itumo esin to daju ni lati ni ife Olorun



Lecture on BG 2.9 -- London, August 15, 1973

Bhagavad-gītā si paari pelu sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). lati ibi ni Bhāgavata ti bere Nitorina Bhagavad-gita ni akeko akọkọṣe ki eyan to ka Śrīmad-Bhāgavatam. Bhāgavata bere pelu dharmaḥ projjhita-kaitavaḥ atra: gbogbo awon esin to ni iyanje Śrīmad-Bhāgavatam si tu gbogbo wa si ita Ife Oluwa ni idi Esin to da. Nitorina Bhagavata so wi pe sa vai puṁsāṁ paro dharmo yato bhaktir adhokṣaje: (SB 1.2.6) "Esin alakoko ni yen Iyen o wi pe egbudo tele esin kan tabi ikeji Eyan le tele Esin to ba fe, ko ba je, Musluman, tabi Onigbagbo, tabi HIndu, ounkooun teba fe Sugbon agbudo se idanwo. gege bi akeko to paari idanwo ile-eko giga Koseni to ma beere pe ati ile-eko wo loti paari Eti paari idanwo ti ile-eko giga? O daa Awa kon femo boya eti paari koseni to ma beeri lati ilu wo, tabi lati esin wo ni eyan ti paari idanwo ile-eko giga. Gege na ko ye ki awon eyan ma beere lati esin wo leti wa? eyan gbudo wo boya eni na ti ni ife Oluwa. Ota. Nkan to je esin ni yen Nitoripe Bhagavata so wipe sarva-dharmān parityajya māṁ ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). Dharmaḥ projjhita-kaitavaḥ atra: gbogbo awon esin to ni iyanje agbudo yo wan kuro ninu Bhagavatam Afi awon nirmatsarāṇām, awon eyan ti o ni ilara fun Oluwa Kini idi ati sin Olorun? Kini idi ati ni ife Olorun? Esu ni gbogbo awon eyan bayi afi awon ton ni ife gidi fun Oluwa Ahaitukī apratihatā yenātmā samprasīdati.

Aseyori ile-aye yi ni igbati eyan ba ni ife fun Oluwa. Nigbana ni Okan wa ma ni itelorun Yaṁ labdhvā cāparaṁ lābhaṁ manyate nādhikaṁ tataḥ. Teba ni Krsna, Olorun ni itumo Krsna. Ti eyin ba ni Oruko imi fun Olorun iyen na da Sugbon Olorun,eyan to gaju Ti eleyi ba ti ye yin Gbogbo eyan lo le ni ife, sugbon awon o mo bon sele ni ife gidi Nitorina Krsna sowipe, Eti gbogbo iranu yi si ita, ke ni ife emi nikan" Sarva-dharmān parityajya mām ekam (BG 18.66). Eyan o le ni itelorun lati Ife ile-aye yi Yenātmā samprasīdati. Te ba fe itelorun gidi, egbudo ni ife fun Oluwa Imoye Veda ni yen Nitoripe itelorun ni gbogbo eyan wa Eleyi asese ti awon eyan ba nu ife Oluwa Nitorina ipo t'alakoko ni esin to ban ko awon elesin re bi wan sele ni ife fun Oluwa.

Sa vai puṁsāṁ paro dharmo yato bhaktiḥ... (SB 1.2.6). kon se ife to fi nkan pamo gege bi ile-aye yi awon eya ma so wipe " Mo feran re" sugbon oni nkan ton wa Ahaituky apratihatā. Ahaitukī, no motive. Anyābhīlāṣitā-śūnyam (Bhakti-rasāmṛta-sindhu 1.1.11). Laisi eto kankan Ema ko gbogbo eleyi ninu Bhagavad-gita.