YO/Prabhupada 0250 - E sise fun Krishna, fun Olorun, E ma sise fun igbadun ara yin



Lecture on BG 2.6 -- London, August 6, 1973

Agbudo mo wi pe emi Ogun jija wa ninu gbogbo eyan Kosi nkan tele se lati fi ipaari si. Awa na o so wipe ke fi ipaari si? Awon Māyāvādī so wipe " efi ipaari si", sugbon ko le sese Ko si be eyin se le fi ipaari si, nitoripe iwa to wa lara yin ni Bawo le se fe fi ipaari si? Sugbon ele lo dada. Otan EYan ni emi jija ogun, Bawo ni eyan na sele lo? Narottama dāsa Ṭhākura ti saalaye krodha bhakta-dveṣī-jane: "E fi ibinu yin fi ba awon ton ni ilara si Oluwa ja" Kosi bi eyan sele fi ipaari si ibinu. sugbon ele lo dada ise ni basele lo awon nkan fun ise to da. Imoye Krsna ni yen Agbudo lo gbogbo nkan, awa o kin so wipe " Ema se tibi, tabi toun" Krsna so wipe yat karoṣi, yaj juhosi, yad aśnāsi, yat tapasyasi kuruśva tad mad-arpanam (BG 9.27). Yat karoṣi. Krsna O so wipe " E ma se bayi " O so wipe " Ounkooun teba se, e fun mi ni esi to fidi re jade" Nibi Arjuna gbudo jagun sugon fun ara re ko O so wipe te avasthitaḥ pramukhe dhārtarāṣṭrāḥ, yān eva hatvā na jijīviṣāmas: (BG 2.6) Awon egbon lon je si mi Koseni to fe ku. Sugbon wan si duro si iwaju mi, Se kin fi iku pa wan? O sin ronu nipa itelorun ara re Awon aye yi man ronu nkan bose ma ni itelorun fun wan Itelorun Krsna ni awa fe, kon se itelorun tara wa Imoye Krsna ni yen. Ko soro pelu Ounkooun teba se Egbudo se idanwo lati mo boya nkan ten se ma fun krsna ni itelorun Aseyori ile-aye yin niyen Idi ile-aye yi ni yen Nitoripe, awon eranko o mo ju igbadun lo wan kin ronu elomi ti nkan jije bawa, aja a ma ronu pe " bawo nimo sele ri kini je" Kole ronu pe bawo ni awon aja toku sele ri je ninu e iwa eranko ko niyen. Itumo Iwa eranko ni itelorun ara wa Ko soro " Ore, tabi ebi" Nigbami wan kin fun awon omo wan gan Ti ounje ba wa, Aja pelu awon omo aja re gbogbo wan lon ma ni apa ototo. Ti eleyi ba yipo fun krsna, ile-aye eda ni yen Iyato si ile-aye eranko niyen. O si le gan Nitorina gbogbo akeko yi wa ninu Bhagavad-gita " E si ise fun Oluwa, ema se ise fun ara yin" Yajñārthāt karmaṇaḥ anyatra loko 'yaṁ karma-bandhanaḥ (BG 3.9). Ounkooun teba se ma ni esi, ema jiya tabi ke gbaduna won esi na Esi wa fun ounkooun teba se, sugbon esi na po teba se fun Krsna Yogaḥ karmasu kauśalam (BG 2.50). Sugbon òmìnira teni niyen Asiri Ilosiwaju ni wipe agbudo ni asepo pelu Oluwa Ninu ile aye yi, oun kooun teba se, ma ni Esi to ba jade ma je ke jiya tabi ke gbadun.

Nkankanna ni gbogbo won. Arjuna ronu na caitad vidmaḥ kataran no garīyo (BG 2.6) O ti ni idamu " Apa wo loma ni isegun? se kin ja tabi kin ma ja" Ni awon page to tele ama saalaye nkan tele se ti eyin na ma ni idamu Eyan gbudo gba eko lodo Oluko Ama soro nipa iyen ni ese-iwe to kan Arjuna ma so wipe " mi o mo, mo ti ni idamu" O ye mi pe ise mi gege bi ksatriya ni wipe kin jagun, sugbon aya min ja Moni idamu, nitorina mi o le se ise i Krsna mo si teriba fun e Teletele arjuna ba krsna soro bi ore ni isin oti di akeko Krsna.