YO/Prabhupada 0251 - Alabasepo t'ayeraye ni awon gopi je si Krishna



Lecture on BG 2.6 -- London, August 6, 1973

Okurin to rewa ni Krsna je, obirin si ni awon gopi nioto oro, alaabaṣepọ ayeraye ni awon gopi je Ānanda-cinmaya-rasa-pratibhāvitābhiḥ (Bs. 5.37). Lati inu Krsna lon ti wa, ise wan ode ju kon se itelorun fun krsna Fun itelorun krsna lon wa fun, wan kin se awon Obirin lasan sugon wan sin ko wa bi a sele ni ife krsna Nitorina ni ale, krsna si pe wan Nigbati krsna fun fere, gbogbo kuro ni ile lo ba krsna Wan si ti awon kan mo le, lesekese wan fi aye si ile Ni isin iru iwa awon Onirin won yi Ni asa Veda awon Obirin o le jade kuru ni itoju baba wan, tabi oko wan, tabi egbon okurin No si bi wan sele jade. ni ale nipataki Asa veda ko leleyi je Bi ise asewo lo je Sugbon nitoripe wan se fun Krsna, Caitanya Mahāprabhu si se àtìlẹ́yìn lori oro na ramyā kācid upāsanā vraja-vadhubhiḥ kalpitā: Kosi aduro to ju ti awon gopi lo. Vraja-Vadhu Ko si ewọ to buru to ti Obirin to kuro ni ile Oko re lo si ile Okurin imi Ni asa Veda, ewọ ni eleyi je Sugbon nitoripe itori Krsna ni awon gopi ti se ewọ yi, ko si aduro to le to ti wan Agudo ko ba sele se ise fun Krsna, gege bi ase le ni ife fun krsna Ile-aye wa a ni ilosiwaju Nitoripe lati Vaikuntha ni awa na ti wa, ni aimoye igba odun to =ti koja Anādi karama-phale. itumo Anādi ni ki iseda to bere, Eda t'ayeraye la je Gbogbo agbaye yi ma pare lehin aimoye odun sugbon awon eda a si wa Na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). wan ma wa Nigbati ile-aye yi ma ni ofin, gbogbo awon eda ma wole sinu ara Visnu ti iseda imi ba bere gbogbo wan ma jade lati le ni itelorun sugbon bi asele pada si Orun ni eto aye wa.

Won si ti fun wa ni aye. Taba lo aye yi ni ilokulo, igbese aye wa ni isoro agbudo pada wa ni aye atunwa Iyen nikan ko, ti awa o ba paari eto aye wa ti ile-aye yi ba fe paare ama tun wole sinu ara visnu nitorina lon se pe ni anādi karama-phale. itumo Anādi ni ki iseda to beere lati le ko awon eda Krsna si ma wa fun ara re Anfaani krsna ni lati mu wa pada losi ijoba re ni orun, nitoripe nkankanna laje pelu e FUn apeere teba ni Omo ton rinkairi loju titi, iwa yi ma di anfaani fun e " àdébá le sele, asi fi iku pa Omo na" Ema jade lowa omo na, gege na ipo Krsna ni yen Awa ninu ile-aye yi, a sin jiya Duḥkhālayam aśāśvatam (BG 8.15). Ibanuje lo kun ile-aye yi Sugbon pelu agbara maya, arope ile-aye ma fun wa ni idunnu. Sugon kosi idunnu ni aye yi, ibanuje ni gbogbo nkan aye yi asiko ta ba le mo wipe ibanuje nikan lo wa ninu aye yi l'asiko na ni ale s'eto bi ase fe jade, kasi pada si ijoba Orun bibeko, ounkooun taba se, ko le si aseyori nibe Nitoripe awa o mo idi nkan tan se. Na te viduḥ svārtha-gatiṁ hi viṣṇum (SB 7.5.31). Durāśayā. gbogbo wa ni ireti...sugbon nkan ti awan reti o le wa A fe ni idunnu ninu ile-aye laini imoye Olorun Ko lesese Na te viduḥ svārtha-gatiṁ hi viṣṇuṁ durāśayā. Itumo Durāśayā ni "Ireti ti o le ni aseyori."