YO/Prabhupada 0252 - Asi rope ale se nkan to wu wa



Lecture on BG 2.6 -- London, August 6, 1973

Gbogbo awon eyan ile-aye yi, asiwere ni wan je. Wan sin s'eto ile-aye yi Wan ro pe ton ba s'eto ile-aye yi wan ni idunnu. Ko le sese Durāśayā ye.. ati Ijoba wan Andhā yathāndhair upanīyamānās te 'pīśa-tantryam uru-dāmni baddhāḥ (SB 7.5.31). Wan ti fi okun so gbogbo wa lat'owo de ese, sugbon arope a le se nkan to wun wa asi rope a ni iminira Awon oni sayensi, wan fe ni nkan se pelu Olorun mo. Kole sese ile-aye ti di wa mu aṣoju krsna ni ile-aye yi Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ sūyate sa-carācaram (BG 9.10). Prakṛteḥ kriyamāṇāni guṇair karmāṇi sarvaśaḥ (BG 3.27). Gbogbo si ni idamu bi Arjuna. awa o mo nkan tale se Sugbon taba ni ofi pe, "agbudo se gbogbo nkan fun Krsna..." E gba ilana lati Krsna, tabi awon aṣoju krsna kode si karma-bandhanaḥ. Karmāṇi nirdaheti kintu ca bhakti-bhājām (Bs. 5.54). bibeko, agbudo jiya gbogbo nkan tati se. Ko si ba sele jade Idamu na de wa " Se kin jagun, tabi kin ma ja" beeni, Agbudo jagun fun krsna. Nigbayen lo ma da Kāmaḥ kṛṣṇa-karmārpane. gege bi Hanumān. O jagun fun Ramacandra. Ko si jagunfun ara re lori àsìá Arjuna aami hanuman si wan be O mo be Jagunjagun alagbara ni Hanuman, O si ba Ravana ja, sugbon fun ara re ko Idi fun ija ni lati gba Sita pada lowo Ravana O si pa gbogbo ebi Ravana, lati le mu Sita jade lo ba Ramacandra ilana-iṣe awon elesin niyen ilana-iṣe ravana ni lati gba Sita fun igbadun ara re ilana-iṣe Ravana niyan, Sugbon ti Hanuman ni lati da Sita pada si Rama Laksmi ni Itumo Sita ohun-ini Narayan tabi Olorun ni itumo Laksmi Gbogbo awon eyan ni ile-aye yi fe gbadun ohun-ini Olorun Sugbon awa o l'agbara lati ba awon eya bi Ravana ja Awa o l'agbara tobe, gege na ati atoro owo je " Ejo, Okurin to rewa le je, Efunwa ni nkan" Nitoripe, ema ba ile-aye yin je teba toju ohun-ini Olorun Sugbon teba di elesin ninu egbe wa, Olorun a si fun in ni igbala Ilana-ise wa niyen. Atoro owo je ko ni wa. sugbon ilana -ise lo je Awa o l'agbara lati ba Ravana ja, bibeko awa o bati fi ija gba gbogbo owo ton ni Ko le sese. Awa o l'agbara. Nitorina lase fe lo ogbon atoro-owo-je. Ese pupo.