YO/Prabhupada 0253 - Wan si salaaye Idunnu gidi ninu iwe Bhagavad-gita



Lecture on BG 2.8 -- London, August 8, 1973

Pradyumna:

na hi prapaśyāmi mamāpanudyād
yac chokam ucchoṣaṇam indriyāṇām
avāpya bhūmāv asapatnam ṛddhaṁ
rājyaṁ surāṇām api cādhipatyam
(BG 2.8)

Itumo, Mi o mo bi mo sele fi ipaari si ibanuje ton fun mi ni idamu Mi o nile fi ipaari si tin ba tie ni Ijoba to gaju ni ile-aye yi tabi ijoba to jo ti awon angeli ni Orun

Prabhupāda: Na hi prapaśyāmi mamāpanudyād. Ipo ile-aye yi niyen Nigbami aye soro, nigbogbo igba gan Awa ro pe Nigbami ni, nitoripe lati koja isoro wanyi agbudo gbinyanju asiko ti awa tin gbiyanju, asiko na dabi idunnu. sugbon idunnu ko lo je Sugbon, asi rope ni ojowaju mo le ni idunnu awon oni sayensi na, wan sin lala pe nijokan awon eyan o ni ku mo Sugbon awon to lopolo wan so wipe "ema fi igbẹkẹle yin si ojowaju"

Ipo wa niyen. Na hi prapaśyāmi mamāpanudyād. Nitorina O ti sumo Krsna: śiṣyas te 'ham (BG 2.7). Nisin mo ti di sisya "Kilode to se wa bami?" " Nitoripe mi o mo elomi to le ranmi lowo ninu asiko to lewu yi" Ogbon gid ni eyi. Yac chokam ucchoṣaṇam indriyāṇām (BG 2.8). Ucchoṣaṇam. Ti eyan ba ni isoro to le gan, nigbami lati ronu ma le gan Igbadun le je ki inu wa dun Ucchoṣaṇam indriyānām. Nibi igbadun ni itumo idunnu. Idunnu gidi ko ni yen Wan si ti juwe idunnu gidi ninu Bhagavad-gītā: atīndriyam, sukham atyantīkaṁ yat tat atīndriyam (BG 6.21). Idunnu gidi ko le ti iye-ara wa Atīndriya, nkan to ju iye-ara lo, Idunnu gidi niyen sugbon igbadun ti di idunnu fun wa Koseni to le ni idunnu lati igbadun ara nitoripe ile-aye yi la wa Iye-ara eke lani, iye-ara gidi ni iye-ara to ya si mimo agbudo taji sinu imoye Oluwa. Gege na pelu iye-ara to ti di mimo eyan le gbadun Sukham atyantikaṁ yat atīndriya (BG 6.21). Ni idari lori iye-ara Idabo ni itumo iye-ara Gege bi i se je ara mi, Ni otooro, arami ko ni mo je, emi ni mi Sugbon ara mi ti di idabo fun emi mi Gege na, arami to ya si mimo na ni iye-ara to je mimo kon se nirakara. kini niarakara? Oro ogbon ori ni Gege bi eyin se ni owo meji Teba si bo owo na pelu aso, ason na ma ni owo Aso mi ti ni owo nitoripe emi na l'owo Nitoripe mo lese, aso ton bo mi na lese Ogbon ori lo je. Nibo ni ara eyan yi ti wa? Wan ti juwe ara gege bi vāsāṁsi, Aso. Wan si ma ge aso gege bi ara eyan na kon se pe wan da ara mi lati le jo aso ti mo wo. Iranu ni yen gege na aso mi ti lowo eleyi rorun nitoripe arami ni owo ati ese, bibeko bawo lose wa.