YO/Prabhupada 0255 - Ni ijoba Olorun awon olori topo si wa, awon angeli lawan pe wan



Lecture on BG 2.8 -- London, August 8, 1973

gege na Krsna le so wipe... mo fe ko jagun, to ba de ti gba ijoba, inure ma dun si Ko si iwuloo pe e fe se mi ni guru.. Gege bi awon eyan ni ile -aye, wan ro pe, mo lowo to po Kini iwulo guru? Mo le ni oye gbogbo nkan bi ose fe" asiwere imi atun so wi pe : Beeni, yata mata tata patha. Ipinnu awon eyan o jo wa loju, nitoripe aw na ni ipinnu tiwa. Nkan ton sele niyen Eyin le ni ipinnu tryin nipa Oluwa Awon asiwere wanyi awon na ni ipinnu ti wan. rara. bee ko Nitorina Arjuna sowipe : avāpya bhūmāv asaptnam ṛddham (BG 2.8). Sapatni je oro tose pataki gan, Itumo re ni ajo iyawo ti okurin ba ni iyawo meji, tabi meta, .. Olorun wa ni iyawo to ko ja ẹgbàájọ. Olorun ni yen Sapatnya, kosoro ifarawe ema ka ninu iwe Krsna nkan ti awon Iyawo re so fun Draupadi gbogbo iyawo re fe di iranse fun Krsna Koseni ton faa ja. Ni ile-aye wa ti okurin ba niju iyawo meta lo, ija ma wa. Apeere na wa ninu Śrīmad-Bhāgavatam, pe gege bi ase ji iye-ara wa ti enikan ba ni iyawo to po, wan ma fa kakiri "wa si yaara mi," iyawo keji na ma sowipe " wa si yaara temi na". Idamu ti wo ori re ni yen gege na gbogbo wa lani awon iyawo wanyi, iye-ara wa Awon oju wa fe lo si sinima Ahon wa fe ka lo si ile-ounjẹ Owo wa fe gbe wa losi ibomi. ese na fe losi ibomi. Ipo aye wa niyen Okurin kanna toni iyawo ton fa kaakiri Ipo wa ni yen, kilode to ri be? Nitoripe iyawo tan ni wan ja sapatnyam ṛddham. Ti awon Oba to po fe ja lori nkan, isoro ma wa Arjuna so wipe: avāpya bhūmāv asaptnyam ṛddham (BG 2.8). " kini iwulo owo ti gbogbo eyan fe gba" Emini kan ko ni mi ni iru owo bayi... rajyam, tabi ijoba surāṇām api cādhipatyam, ijoba taye yi nikan ko, sugbon ijoba torun gav Awon eya nisin fe losi Osupa Sugbon ijoba imi niyen Awon eda toyato lo wa ni ijoba yen Awon Orisa lon wan be, wan si l'agbara gege bi Indra, alagbara ni Indra je oun lo ni idari lori Ojo. Osi ni Ara Awon eyan onigbagbo, sugbon awa ni Agbudo ni igbagbo Otooro ni. Nibo ni Ara tin wa? Ta lon ran Omi-Ojo? Eyan kan wa nidi gbogbo e gege bi ile-ijoba, orisiri ẹka ile iṣẹ lo wa gege na ni ile-ise Olorun, oludari orisirisi lo wa awon oniise. Orisa ton yato si ara wan. Devarṣi-bhūtāpta-nṛṇāṁ pitṟṇām (SB 11.5.41). Awon Orisa sin se ise labe Olorun, gege bi Indra ton seto Omi-Ojo Ebo orisirisi lo wa lati s'adura fun awon Orisa wanyi Krsna si fi ipaari si ebo ton gbe fun Indra, nigbati Nanda Maharaj, fe gbe ebo fun Indra, krsna so wipe: "baba mi, kini iwulo ebo te fe gbe fun Indra" Itumo yen ni wipe enikeni to ba wa ninu imoye Krsna ko ni iwulo fun ebo si awon Orisa. Nipataki, ni asiko tawayi osoro lati gbe ebo Eyen se se ni aye Treta-yuga Kṛte yad dhyāyato viṣṇuṁ tretāyāṁ yajato makhaiḥ (SB 12.3.52). Makhaiḥ means yajña, performing yajña. Yajñārthe karmaṇo 'nyatra loko 'yaṁ karma-bandhanaḥ (BG 3.9). Kole se se ni asiko tawayi sastra si sowipe: yajñaiḥ saṅkīrtanair prāyair yajanti hi sumedhasaḥ. Awon ton logbon wan se ise saṅkīrtana-yajña. Oroto wa ninu sastra niyen