YO/Prabhupada 0256 - Ni ile-aye Kali-yuga tawayi Krishna sifarahan si waniu oruko re, Hare Krishna



Lecture on BG 2.8 -- London, August 8, 1973

kṛṣṇa-varṇaṁ tviṣākṛṣṇaṁ
saṅgopaṅgāstra-pārṣadam
yajñaiḥ saṅkīrtanaiḥ prāyair
yajanti hi sumedhasaḥ
(SB 11.5.32)

Kṛṣṇa-varṇaṁ tviṣākṛṣṇam, Caitanya Mahāprabhu leleyi Krsna na ni oun je, sugbon kikọdi ara re ko jo ti Krsna, ara re o dudu. akrsna Kṛṣṇa-varṇaṁ tviṣa... kikọdi ni itumo Tvisa. Akrsna. pupa Saṅgopaṅgāstra-pārṣadam, awon alaabaṣepọ siwa pelu re Nityānanda Prabhu, Advaita Prabhu, śrīvāsādi gaura-bhakta-vṛnda. Olorun to ye ka gbadur si ni ile-aye yi. Kṛṣṇa-varṇaṁ tviṣākṛṣṇa. Kini Ilana adura? Yajñaiḥ saṅkīrtanair prāyair yajanti hi sumedhasaḥ. Ise saṅkīrtana-yajña ti awa nse niwaju Caitanya, Nityānanda ati awon alajosepo re ise ebo to gaju ni asiko tawayi Bibeko, kosi imi. Nitorina ise na ti ni ilosiwaju yajna ton juwe fun wa niyen, awon yajna iyoku bi Rājasūya yajña, Orisirisi yajna lowa, nigbami ni orile-ede India awon eyan ma se yajna orisirisi wan kon gba owo. Otan Ko le ni ilosiwaju nitoripe kosi yajnic brāhmaṇa awon yajnic brāhmaṇa o si laaye yi mo awon yajnic brāhmaṇa wanyi wan le se idanwo lati mo boya wan faṣẹ sọrọ dada esi idanwo na ni wipe wan ma fi eranko sinu ina asi jade pada pelu ara to dara ton ba de ti paari yajna wan si se idanwo na Awon brahmana ati awon yajnic brahmana wan mo bosen faṣẹ sọro Idanwo niyen. Sugbon ni aye isin nibo ni brahmana na wa? nitorina wan ti fi ipaari si awon yajna Kalau pañca vivarjayet aśvamedham, avalambhaṁ sannyāsaṁ bāla-paitṛkam, devareṇa suta-pitṛ kalau pañca vivarjayet (CC Adi 17.164). gege na kosi yajna ni aye isin, ko de si awon yajnic brahmana yajna to wa fun aye yi ni orin Hare krsna. ekorin ke jo.

So rājyaṁ surāṇām api cādhipatyam (BG 2.8). teletele awon Esu gba ijoba lowo awon ageli Rājyaṁ surāṇām api cādhipatyam. gege bi Hiraṇyakaśipu. Osi gba ijoba lowo Indra gan Indrāri-vyākulaṁ lokaṁ mṛdayanti yuge yuge (SB 1.3.28). Indrāri. Ota Indra ni itumo Indrari Indra ni Oba isọgbe-oorun, Esu ni awon Ota re gege mi awa na se ni awon Ota to po awa sini Ota to po nitoripe awa n'korin hare Krsna wan o fe ka korin mo. Ni isn wan ti po gan. Teletele iwonba die lowa, nisin wan ti po ga indrāri-vyākulaṁ lokam ti awon esu bay ba posi iye awon Esu na ma posi nitorina vyākulaṁ lokam awon asi ni idamu, ndrāri vyākulaṁ lokaṁ mṛdayanti yuge yuge. Nigbayen krsna na asi wa. Ete cāṁśa-kalāḥ puṁsaḥ kṛṣṇas tu bhagavān svayam (SB 1.3.28). Awon oruko Olorun gege bose je nigbati owa sinu aye yi Sugbon lehin igbati Bhagavata ti daruko wan tan, O so pe " gbogbo oriuka ta pejo sibe aṣoju ti apá kan lan je si Krsna Sugon Oruko Krsna si wa ni be... Kṛṣṇas tu bhagavān svayam. ... Indrāri-vyākulaṁ loke nigbati idojuti ti awon esu bati koja nkan ti awon eyan le gba, nigbayen Olorun ma wa Oun na jerisi. Sastra niyen sastra kan sowipe , bayi loma wa krsna so wipe yadā yadā hi dharmasya glānir bhavati bhārata... tadātmānaṁ sṛjāmy aham: (BG 4.7) nigbana ni moma wa.

Ninu asiko Kali tawa yi, idamu awo eyan po gan Nitorina krsna ti wa ni irisi Oruko re, hare krsna krsna fun ara re ko lowa, sugbon ninu oruko re sugbon ko si iyato laarin oruko krsna ati krna fun ara re nitoripe ọlọ́̀gangan ni Krsna je Abhinnatvān nāma-nāminoḥ (CC Madhya 17.133). Nāma-cintāmaṇi kṛṣṇa-caitanya-rasa-vigrahaḥ pūrṇaḥ śuddho nitya-muktaḥ. Odindi ni krsna je, gege bi oruko re na Suddha. Nkan aye yi ko. Pūrṇaḥ śuddhaḥ nityaḥ Gege bi krsna se je eyan tiolopin, alailopin ni Oruko re na Pūrṇaḥ śuddhaḥ nitya-muktaḥ. Kosoro ìròiyè inú ti aaye yi ni orin Hare Krsna Abhinnatvān nāma-nāminoḥ. Nāma, Oruko Olorun pelu Olorun fun ara re nkankanna lon je, abhinna, kosiyato Rājyaṁ surāṇām api cādhipatyam (BG 2.8) Botielejepe, ani ijoba ni tawan Angeli, asapatya lai si awon eyan to fe farawe wa ko si ba sele ni iduuna na, nitoripe asi wa ninu ile-aye . Ko le sese Itumo ese-iwe niyen Ese pupo. Otan