YO/Prabhupada 0257 - Bawo lesefe koja ofin Olorun



Lecture -- Seattle, September 27, 1968

Etoo ni bi asele se ijọsin fun Olorun Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi. Ni ile-aye yi gbogbo wa la fe ni idunnu ati itura lowo isoro aye wa awon nkan meji ton sele ninu aye niyen ilana meji toyato lon je Ilana ile-aye yi ko sogbon ninu e. Ko si iwonba idunnu to le fun ni ifokanbale ninu aye yi Kolesese. Awon ilana toyato na si wa Isoro meta lo wa, ādhyātmic, ādhibhautic, ādhidaivic. itumo Ādhyātmic ni awon isoro ton wa lati okan ati ara wa gege bi igbati ara ba ni inira taba ni iba, tabi irora, tabi orififo.. awon isoro ara wanyi, Ādhyātmic lon pe wan apa keji isoro Ādhyātmic lati okan niyen tin wa Fun apeere tin ba ni ipadanu, okan mi o le bale ijiya niyen na aisan ati alainifokan bale isoro ni awon meejeji je ādhibhautic - isoro lati awon eda ototo gege bi awon eyan ton ran awon eranko topo lo si ile-ton peran wan sile soro, ādhibhautic niyen ijiya ton wa lati awon eda gege na awa na ni lati jiya lowo orisirisi eda Koseni to gaju Ofin Olorun lo eyan le se ko ma tele Ofin ijoba sugbon ti Olorun ko lesese ani awon ijeri to po Ijeri ni OOrun je, Ijeri ni osupa je, Ijeri ni oju-ojo je, Ijeri ni Ojo-ale je, ijeri ni ofurufu je Bawo ni eyan sele sapamo fun ofin Oluwa/ Sugbon wan da ile-aye fun ijiya wa Ādhyātmic, eyi to ni lati se pelu ara ati okan wa Ijiya lati orisirisi eda, ādhidaivic. niyen je Ādhidaivic, gege bipe iwin dêrùbà eyan koseni to le foju ri iwin, sugbon eyan tin iwin ban deruba eyan eni na ama so iokuso iyan, iji ilẹ, ogun, wan si po gan gege na ijiya wa nigba gbogbo sugbon awon eyan sin faramo gbogbo eyan lon jiya, beena ni gbogbo eyan fe fi ipaari si ijiya na idi ile-aye yi ni lati le jade kuro ninu ijiya yi sugbon orisirisi iṣeduro lowa eyan kan le sowipe, ilana tele fi jade kuru ninu ijiya leleyi, elomi asi so nkan mi awon onisayensi na ti fun wa ni ilana to po gege bi awon, Onigbagbo, ati alainigbagbo... wan po gan Sugbon ninu esin Imoye Krsna, ona soso ti eyan le gba jade ninu gbogbo isoro wanyi ni ti enina ba le yi imoye re pada, otan Imoye Krsna niyen mo ti fun apeere to po teletele... gbogbo ijiya wa lati aimo nkan loti wa te ba ni asepo pelu awon olori to da, eyin na le ni imoye na.