YO/Prabhupada 0261 - Lori ipo kanna ni Oluwa ati awon elesin re wa



Lecture -- Seattle, September 27, 1968

Prabhupāda: Awon okurin yi sin gbiyanju lati se iwaasu imoye Krsna ni Orile-ede yin gege na ìbéèrè kan soso ti moni ni wipe ke gbiyanju lati ni oye ibukun si aye wa teba si korin hare Krsna ema bere lati ni ife fun Krsna Lesekese teba bere lati ni ife fun Krsna, gbogbo Isoro Ema ni idunnu repete. lati Okan yin ni isoro tin wa okurin ka le ma gba $6000 ni osu ki ikeji ma gba $200 ni osu sugbon mo ti ri eyan to pokunso ni ilu Calcutta to de je pe 6,000 ni owo osu ton gba kilode to pokunso? Owo na oto lati fun ni idunnu. O si fe dan nkan mi wo. Ni ile aye yi, ko si aduro owo tele pa to ma fun yin ni idunnu te fe, nitoripe iranse laje si iye-ara wa Ipo iranse si iye-ara agbudo yipada ka le di iranse fun Krsna Nigbana a ma ri ona abayo si gbogbo isoro aye wa. Ese pupo (awon elesin teriba) Se eni ibeere?

Elesin: Prabhupāda, se ọlọ́̀gangan ni iworan Krsna je? Sale sobe fun iworan awon eyan ton ti di mimo?

Prabhupāda: Iworan awon elesin to ti ya si mimo?

Elesin : Eyan toti di mimo

Prabhupāda: Beeni.

Elesin: se nkankanna lon je

Prabhupāda: Beeni.

Elesin: Ka sowipe iworan Prahlada Maharaja ati Nrsimha-deva... Prahlada na si wa ninu iworan gege bi Nrsimha-deva

Prabhupāda: Beeni. Olorun pelu awon alabasepo re, ipo kanna lon wa Oruko Olorun, Ara re, amuye re, awon alabasepo re, gbogbo nkan. ọlọ́̀gangan ni wan je. Nāma guṇa rūpa līlā pari.. ati idaraya Gege bi awa sen gbo nipa krsna, kosi iyato si krsna Taba sin korin Hare Krsna ko yato si krsna ọlọ́̀gangan ni gbogbo nkan aye yi. Nitorina awon elesin Krsna ton ti ya si mimo kosi iyato laarin wan ati krsna Nkankanna pelu iyato lo je. Acintya-bhedābheda-tattva Agbudo ni oye imoye pe Olorun ni Krsna je pe, gbogbo nkan tan foju ri, agabara ototo krsna lon je kosi be sele ya sọtọ agbara lati alagbara nitorina ipo kannalon wa ti māyā tabi aimokan ba si bo, iyen yato. Otan.