YO/Prabhupada 0262 - Oye ke rowipe ise tense fun Olorun ko si to



Lecture -- Seattle, September 27, 1968

Tamāla Kṛṣṇa: Prabhupāda, Nigbami amo wipe agbudo se ise fun Olorun, sugbon ise na o baramu.

Prabhupāda Beeni. Ema ro wipe ise na ma da gan Eleyi ma fi e si ipo to da. O ye ka ronu pe, ise ta se fu Olorun o da to. Nkan to da niyen gege bi Caitanya Mahāprabhu se so fun wa.. O so wipe " Eyin ore ejo mofe ke mo wipe, mio ni igbagbo kankan ninu Krsna. Ma si sukun teba soro bayi Mo kan daaun lati sebi wipe elesin ni mo je Sugbon mi o ni igbagbo ni Krsna Ekun ti mon sun, ekun eke lo je Nisin eyin gan le ri pe, mo si walaaye laisi Krsna Iyen fi hon pe, mi o nife fun krsna. Bibeko Oye kin ti ku tipe lairi Krsna Agbudo ronu bayi.. Apeere to da fun wa Elema se ise to da gan fun Krsna sugbon o ye ke mo wipe alainiopin ni Krsna je, gege ko si ise tele se fun to le ka asi kun fu aṣiṣe nitoripe gege bi eda eyan awa ni opin Sugbon krsna si dara gan. Iwonba ise kekere teba se, om gba be Iwa rere krsna ni yen. Svalpam apy asya dharmasya trāyate mahato bhayāt. ti Krsna ba gba ise die teba se fun, ile-aye yin ti da ni yen gege na ko lesese pe eyan nife to dara to fun krsna, nitoripe alainiopin ni Krsna ilana kan wa, a s'adura si Ganges ni Orile-ede Odo mimo ni Odo Ganges je gege na awon man s'adura si Odo Ganges Ti eyan ba s'ẹbọ si Ganges pelu omi lati Odo na ele fi die sinu owo yin tabi sinu ikoko Ele mu omi die lati Ganges ke si gbadura si Odo na eyan bu omi lati Ganges lati fi s'ẹbọ fun ganges Nibo looro ipadannu tabi èrè fun Ganges? Ke si bu omi lati Ganges tefi s'ebo fun Nibo looro ipadannu tabi èrè fun Ganges? Sugbon ilana te fi se, igbagbo teni, ife yin fun Iya Ganges "Iya Ganges, mo si fe fun yin ni Omi kekere yi". Eleyi se se gege na, kilani lati fun Krsna? Oun ni Olori gbogbo nkan Asi fun l'eso. Saawa la ni eso? Talo si da awon eso na? Seemi ni mo da wan? Sooni Opolo eyan kankan to le da eso, tabi wara Awon onisayensi, se wan le se Awon maalu je ewe wa si fun wani wara Se ele so ewe di wara pelu sayensi? Sugbon awon asiwere wanyi O fe gba pe Olorun wa. Se ri bayen? Wan si ti di asiwere. Sayensi. Kini Sayensi, Iranu? Se ri bi awon maalu sen je ewe wa si fun wa ni wara sel fun iyawo yin l'ewe je kosi fu yin ni wara? kilode te fin ra wara l'oja? teba fun eyan ni awon ewe je, ema fi iku pa Ofin Krsna tabi Ofin Olorun lon se ise yen "Wan si so wipe Olorun ti ku. Ko s'Olorun. Olorun ni mo je" Bi wan sen se niyen. Wan ti di Asiwere ati Ode Kilode ti wan o se wa fun apejo yi? "Oh Swamiji yi fe soro nipa Olorun, nkan ayeatijo (erin) ejeka wa nkan tutun. " Se ri"? Sugbon ti elomi ban so isokuso.. Fun wakati merin, iranu lo so.. Okurin ni ilu Montreal so wi pe " Swamiji oni enikan to soro fun wakati merin lori oro " odo" seri bayi, fun wakati merin wan fe gbo nipa "odo" (erin) kini iwulo "odo"? kilode tefe lo wakati merin ni ilokulo? nkan ti awon eyan fe niyen Taba so awon nka bi " Alagbara ni Oluwa, iranse oluwa ni gbogo wa. Koseni to l'agbara, Oluwa lon s'eto gbogbo wa E di elesin Olorun, inu yin asi dun". Koseni to feran iru oror bayi Wan fe ki awan eyan yanwa je. nitorina awon ton ma yanwa je ma wa. Otan wan feran iyanje. Awon eyan o feran nkan to rorun.