YO/Prabhupada 0266 - Brahmacari to gaju ni Krishna je



Lecture on BG 2.10 -- London, August 16, 1973

Prabhupāda: Bhismadeva si so wipe Kosi brahmacari todaju krsna lo O wa laarin awon gopi, awon omo obirin sugbon o si je brahmacari Toba jewipe emi nimo wa pelu awon gopi mio mo nkan to ma sele Nitorina brahmacari to da ni Krsna je, Hṛṣīkeśa. awon asiwere wanyi si sowipe onisekuse ni Krsna je brahmacari to gaju ni Krsna Itumo Dhira ni eyan toni ifarabale niwaju awon nkan tole ru nkan soke Brahmacari ni krsna osi wa lasiko odo re, bi awon omo odun medogun, tabi merindinlogun gbogbo awon omo-obirin ninu abule na si feran Krsna gan nitoripe o rewa gan wan si man wa jo pelu krsna sugbon brahmacari lo je Kosibi tele gbo pe krsna ni asepo pelu obirin O ba awon gopi jo, sugbon ko soro ẹlaa magboyun Iyen o sele. Nitorina Hrsikesa lo je itumo Hrsikesa ni brahmacari to gaju Vikāra-hetu, toba ni idi lati ni ikanra, koni se. Osi ni aimoye elesin ti gbogbo wan ba fe di Ololufe si Krsna asi gba gbogbo wan Kosi ni iwulo fun enikankan. Ote ara re lorun, koni iwulo fun enikankan lati le gbadun ara re nitorina Hrsikesa ni Krsna gege na awon elesin krsna...

Gbogbo awon elesin Krsna, wan ni idari lori iye-ara wan gege bi Haridasa Thakura, se mo. Musluman ni Haridas Thakur je, onile lo je Gbogbo eyan sin pe ni elesin to ga gan gege na awon onile ni abule na, si bere sini ni ilara fun wan si pe aṣẹwo kan pe kolo damu Haridas Thakura Obirin na si wa ni ale, osi mura dada, osi lewa gan Obirin na si lewa pupo Obirin na si so wipe, "mo ti wa si ibi lati wa ba yin nitoripe moni ifara si eyin Haridas Thakura so wipe, " Beeni. E joko" ejekin gbadura mi tan, lehin na ama gbadun ara wa Obirin na si joko Sugbon Haridas Thakura berin sini korin, O le fun wa lati korin fun asiko merindilogun, sugbon oun korin fun asiko meridinlogun lona meta Melo niyen je?

Revatinandana: 196.

Prabhupāda: igba 196. Ise soso ton se niyen Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa, Kṛṣṇa Kṛṣṇa... Nigbami awon eyan ma fe farawe Haridas Thakur. Kole sese Ni ojo keji, asewo na si so wipe, " Oga oti daaro" Ma pada wa ni ale, Beeni pada wa lale. Mi o le paari orin mi laana Nkan to so fun niyen, sugbon ijo meta si koja bayi Asewo na si ni iyipada ni okan re, Osi teriba "Oga, Mo wa lati ni asepo pelu yin. Eyan ti o da nimi" E dariji mi Haridas Thakur si sowipe, Mo le kuro nibi nigbato wa sugbon mo si rope mo gbudo so e di elesin Gege na asewo na si di elesin Olorun nitori ore-ofe .. Haridas Thakur si so fun, "joko si ibi" Korin Hare Krsna niwaju irugbin tulasi. Mo fe kuro nibi.