YO/Prabhupada 0270 - Gbogbo wa lani iwa adayeba



Lecture on BG 2.7 -- London, August 7, 1973

Pradyumna: Itumo, Nisin mio mo nkan ti ise mi je, gbogbo ifakanbale mi si ti pare nitori ijaya Gege bi mo se wayi, mofe ke sofun mi nkan to da fun mi Mo ti di akeko si e, mo de ti teriba. Ejo efunmi ni ilana nkan ti mole se

Prabhupāda: ese-iwe tose pataki gan ninu iwe Bhagavad-gita leleyi Iyipada ninu aye eyan lo je Kārpaṇya-doṣa. alahun. eso ni itumo dosa enikeni ti o ba huwa gege bo se je, asise re niyen alahun ni eyan na je gbogbo eyan si ni iwa ti e, svabhava Yasya hi svabhāvasya tasyāso duratikramaḥ. Svabhāva, ifarahan adayeba lo je yasya hi yaḥ svabhāvasya tasyāso duratikramaḥ. Apeere ti awa man lo gan.. ihuwasi ni àsà je si awon eyan. tabi eyan toni iwa ti oda, kosi le tunse asi ni apeere imi: śvā yadi kriyate rājā saḥ kiṁ na so uparhanam. teba so aja d'oba, se iyen wipe koni la bata awon eyan? Iwa aja ni lati la bata awon eyan teba wo aja na laso, kesi fi sori itẹ ọba lesekese toba ri bata, afo sile ade bere sini la bata na Svabhava niyen. Karpanya-dosa.

Ni ile-aye awon eranko, kosi bon sele fi iwa toni sile, Nkan ti agbara aye yi ti funwan niyen Prakṛteḥ kriyamāṇāni (BG 3.27). Kāraṇaṁ guṇa-saṅgo 'sya, kāraṇaṁ guṇa-sangaḥ asya sad-asad-janma-yoniṣu (BG 13.22). kilode? nkankanna ni gbogbo awon eda je pelu Olorun ni alakoko gbogbo wa lani iwa bi t'Olorun oro iwonba loje àmúyẹ kanna loje, sugbon iye oto loje Mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ (BG 15.7). teba bu omi die lati omi okun, nkankanna loje ni amuye sugbon iye yato si rawaon. Okun si tobi gan gege na awa sini iwa tojo ti Krsna Kilode ti awon eyan sen so wipe Olorun oni amuye eyan to wa laaye? T'emi ati Olorun taba ni amuye to jora, kilode to je pe eyan ko lo je? Kilode te rope Olorun oni awon amuye bi eyan? iranu imi tuniyen. Alaini oye Olorun ni Awon asiwere wanyi Ninu iwe Bibeli, wan si sowipe " " Olorun si da awon gege bi ara re" Elemo nipa Olorun teba mo nipa ara yin Oro iye nikan lowa Moni awon amuye kan... gbogbo wa lale da nkan le.. sugbon nkan to ba da kole to nkan ti Olorun ma da. Iyato to wa niyen ati da ẹrọ ton fo soke Igberaga wa ti posi nitoripe ati da sputnik to le fo losi Osupa sugbon asi pada wa. Ko daa to Sugobn Olorun ti da awon isogbe ton si wuwo gan ton si fo l'ofurufu gege bi Isogbe wa sen fo pelu awon okegiga at'Okun O si le fo ni ofurufu gege bi owu. Agbara Olorun niyen. Gām āviśya (BG 15.13). Ema ri ninu Bhagavad-gita: ahaṁ dhārayāmy ojasā. ta lon toju gbogbo isogbe-orun wanyi? ninu sastra awa ti ri pe Saṅkarṣaṇa. lon gbe wan