YO/Prabhupada 0273 - Itumo Arya-samana ni eyan toni imoye Krishna



Lecture on BG 2.7 -- London, August 7, 1973

Eyan pelu okan to fe ni brahmana je Etad viditvā prayāti sa brāhmaṇaḥ, Nitorina Prahlāda Mahārāja so wipe: durlabhaṁ manuṣyaṁ janma adhruvam arthadam (SB 7.6.1). Osi se iwaasu laarin awon ore re wan si bi sinu ile awon esu, Hiraṇyakaśipu awon ore rena, tan wa ni ipo kanna Prahlāda Mahārāja si sofun wan, Eyin Oremi ejeka gba imoye Krsna sokan awon omode-okurin, kilon mo nipa imoye Krsna? Eyan toni igbala lati igbato je omode ni Prahlada maharaj Wan si bere lowo re " Kini itumo imoye Krsna?" O si so fun wan: urlabhaṁ manuṣyaṁ janma tad apy adhruvam arthadam. durlabham ni ara eyan je Labdhvā sudurlabhaṁ idam bahu sambhavānte (SB 11.9.29). Nkan to dara ni ara eyan tani sugbon awon eyan o logbon awon eyan yi o mo iyi ara eyan. wan si n'se isekuse pelu ara wan bi awon aja ati ologbo Sastra si sowipe " Ile-aye wa gege bi eyan fun igbadun bi awon aja ko lo wa Nāyaṁ deho deha-bhājāṁ nṛ-loke. gbogbo eyan loni ara ninu aye yi Sugbon ni awujo awon eyan, agbudo lo ara wa dada. nṛ-loke, Nāyaṁ deho deha-bhājāṁ nṛ-loke kaṣṭān kāmān arhati viḍ-bhujāṁ ye (SB 5.5.1). Ti eyan ba lo igbese aye re lati fi gbadun nikan, ilokulo niyen ise awon aja ati elede niyen sugobn wan s'ise gege bi awon eranko na lati gbadun ara wan gege na ninu awujo awon eyan, agbudo se iyasoto nkan ton pe ni varṇāśrama-dharma. Tabi Ārya-samāja. kon sepe ka di asiwere, kama ni igbagbo ni Olorun. itumo Ārya-samāja ko niyen Anarya niyen. gege bi Krsna se sofun Arjun: anārya-juṣṭa. O sen soro bi anārya. Eni to bani oye krsna anārya lo je Anārya.Enikeni to ma ni ilosiwaju ni eto imoye Krsna ni Ārya gege na awon Ārya-samāna to daju ni awon toni imoye Krsna. bibeko, iranu niwan Nitoripe, ninu iwe Bhagava-gita Krsna sowipe Arjuna ko lati jagun nitoripe ko mo nkan ti ise re je Arjuna si gba wipe kārpaṇya-doṣopahata-svabhāvaḥ (BG 2.7). anārya ni mo je nitoripe mo ti gbagbe ise mi.

Itumo āryan samāja ni awujo awon eyan toni imoye Krsna Egbe fun gbogbo aye.. ārya niyen Arjuna si salaaye kārpaṇya-doṣo nitoripe mo ti gbagbe ise mi, mo ti bosi inu owo idamu ile-aye yi eyan to je ksatriya o gbudo yoole Ti ogun ba wa, ogbudo ni ina-okan lati ja Ti ksatriya kan ba sofun ksatriya imi pe "mo fe ba e ja" ko gbudo salo "Beeni, wa ka ja", Asi gbe idà lesekese asowipe, "Wa ka ja". Ko le se ko ma ja Nitorina Oni oye.. Oti gbagbe ise re gege bi ksatriya. Osi jewo..kārpaṇya-doṣa Kārpaṇya-doṣopahata-svabhāvaḥ (BG 2.7). Moti gbagbe ise toye kin se Ti eyan ba di alaun, aisan lo je kini ise toye ko se? gege bi eyan to ba ni aisan, aloba ologun asi bere "kini mole se?" Moni aisan bai.. gege na ti eyan o ba mo nkan to ye ko se, o le gbagbe ise re o si da ko lo si eyan to gaju lo kosi beere Talo le ju Krsna lo? Nitorina Arjuna sowipe: Prchami tvam " Mosi berelowo re" Nitoripe ise mi lo je. Mio mo nkan ti ise mi je> Agbudo beere lowo eyan to gajuwa lo ise wa niyen. Tad vijñānārthaṁ sa gurum eva abhigacchet (MU 1.2.12). Ise gege bi Veda se so Gbogbo eyan lo ni idamu ni ile-aye yi. Sugobn koseni to fe wa Oluko to ma ko. rara kārpaṇya-doṣa niyen. Arjuna si fe jade kuro ninu kārpaṇya-doṣa. bawo? Nisin oti bi krsna. Pṛcchāmi tvām "Krsna mi, eyin ni eyan to gaju ninu aye yi" Mo mobe. Krsna le je> sugbon mio mo nkan to ye kin se moti gbagbe ise mi, nitorina mo se wa beere.