YO/Prabhupada 0279 - Ni otooro gbogbo wa lan sise fun owo



Lecture on BG 7.2 -- San Francisco, September 11, 1968

ninu ese-iwe yi, wan si ti salaaye pelu alaaye lori eni to ye ka gbadura si Gbogbo eyan lon s'adura , fun eni ta fe awon sin s'aduro si oga wan Fun apeere toba jewipe, mon sise ni ile-ise timo sini Oga Oye kin tele nkan to ba so. gege na gbogbo eyan s'adura s'eyan kan Nisin, oye ka mo eyan to ye ki gbogbo agbaye gbadura si, Krsna. Oun ni eni to le gba gbogbo adura wa, wan ma salaaye ni apa-iwe ta fe ka Ya svarūpaṁ sarva karaṁ ca yac ca dhiyāṁ tad ubhaya-viṣayakaṁ jñānaṁ vyaktum atra bhakti-pratijñānam. Nitorina ti awa ba mope Oludari to wa leleyi gbogbo isoro ninu aye wa ma tan lesekese. Nijokan mo si sofunyin nipa Okurin musluman to fe s'adura si eni to gaju ni aye yi Osin s'ise fun Nawab, lehin na s'ise fun Oloye, Badshah, lat'odo oloye na o lo si odo Haridas, aalufa loje lat'odo Haridasa o bere sini s'adura si Krsna ni ilu Vrndavana.

Agbudo logbon. Gbogbo wa lan s'ise. A sin s'ise fun iye-ara wa. gbogbo eyan lotidi iranse si iye-ara wan,... Timo ba di iranse fun enikan, niotooro nitori owo re nimo sen sise fun To ba sowipe " ni ola wa sise funmi, laisi owo Mon son dollar ogun fun yin sugbon l'ola ema sise gb'owo nitoripe miolowo. ama kpariwo "rara mi o wa niyen, owo nimo sise fun, eyin ko" gege na owo ni gbogo wan sise fun. Kilode to je pe owo lan sise fun? Nitoripe pelu owo ale gbadun ara wa lais'owo kosi basele gbadun ara wa Tin ba femu, tin ba fe gbadun, oye kin lowo Nitorina, moti di iranse iye-arami.

Nitorina la sen pe Krsna ni Govinda gbogbo wa la fe gbadun, iye-ara ni itumo go Eledumare losi wa nibi teba sise fun Krsna lehin na ema ni itelorun Nitorina ni oruko re se je Govinda Gbogbo wa lafe gbadun ara wa, sugbon oye ka seto bi asele se igbadun fun Krsna, Govinda Nitorina itumo bhakti ni wipe, aso iye-ara wa di mimo pe adi iranse ninu ise Oluwa. Ninu apa kewa ni iwe mimo Bhagavad-gita ema ri ibi ti Arjuna ti juwe Krsna pavitraṁ paramaṁ bhavān: "Enimimo to gaju leje" gege na taba di ranse fun eni toni iye-ara to yasi mimo ju lehin na,awa na le yasi mimo pe eyan yasi mimo itumo re niwipe eni na si ni oye nipa emi Oye nipa emi ni itumo ile-aye to yasi mimo, lehin aye to doti ni ile-aye yi gege bi awa se ni ara, sugbon t'ile-aye yi ni ara wa tiwa Nitorina lase ni aisan, lasele darugbo asi ni ibimo, asi le ku ni Ipo wa, ni irisi wa to yasi mimo, ko soro ijiya Kosi ibimo, kosoro iku, ko soro aisan, kosoro ojo arugbo ninu Bhagavad-gita wa si sowipe, nityaḥ śāśvato 'yaṁ na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). botilejepe emi ni mo darugbo ju, nitoripe ara mi ni iyipada.. Emi nimo je, mosi yasi mimo Mio ni ibimo, tabi iku, arami kon ni iyipada, nitorina emi ni mo darugboju. Emini mo darugbo ju sugbon tuntun l'emi mmi je tuntun nimo je. Ipo mi niyen