YO/Prabhupada 0282 - Agbudo tele ifẹsẹtẹ awon Acaryas



Lecture on BG 7.2 -- San Francisco, September 11, 1968

manuṣyāṇāṁ sahasreṣu
kaścid yatati siddhaye
yatatām api siddhānāṁ
kaścin vetti māṁ tattvataḥ
(BG 7.3)

Nibi wan si sowipe manuṣyas teṣāṁ śāstra 'dhikara yajñānāṁ sahasra-madhye. Tani mi, Tani Olorun, kini itumo ile-aye yi, bawo lo sen sise ise awon eyan to l'eko leleyi Eyan ti ol'ogbon ko si bosele gba gbogbo eleyi. nitorina śāstra adhikāra. Itumo Śāstra niwipe eyan tini imoye ninu awn iwe imoye wanyi lesekese teba ri eyan to ni imoye lati awon iwe, iwonba awon eyan ti o ki oye na si kere teba si fe wa di lati mo eyan melo ni o l'eko, ema ripe wan po gan. gege na, teba fe mo awon eyan melo lon ni esi lati iwe-eko giga, ema ripe wan si kere si Gege na awon eyan po ninu ile-aye yi, sugobn teba fe ri eyan to ti fun ara re fun krsna., lesekese lon ma dinku laarin awon eyan bayi ema ri awon, swami, yogi,.... teba si ka laarin wan lati mo awon eyan toni oye Olorun, tabi imoye Olorun, wan ma kere si

Nitorina Krsna se sowipe, laarin aimoye awon eyan boya lema ri enikan toni anfanni lati so ile-aye re di mimo gege na laarin aimoye awon ton fe so ile-aye wan di mimo boya lema ri enikan to mo Olorun tabi Krsna sugbon Krsna si ni-ife wa, gege na asi wa fun ara re kaba le ni oye nipa re nitori ife tosi ni fun wa koto kuro lati ile-aye yi, asi fi Bhagavad-gita le fun wa bayi elemo nipa Olorun lati awon nkan to so fun ara re Gege n ateba si ka Bhagavad-gita bi Krsna se so, lai fi alaaye iranu si laisi awon itumo iran, sugbon gege bose je Osi da ka salaaye awon nkan gege bon se je, Krsna sowipe " Olorun, nimi" Ema fun iwe na ni itumo iranu, sugbon egba Krsna gege bi Olorun fun ara re Esi le mo teba wo awon nkan to se, awon nkna to so, gbogbo eyan ni ile-aye atijo lo mo

Agbudo tele ifẹsẹtẹ awon ācāryas. Mahājano yena gataḥ sa panthāḥ (CC Madhya 17.186). Kosi basele ni oye nipa awon nkan toye ka mo t'awa o tele awon eyan to se pataki gege bi sayensi, wan ni ofin iwale gbogbo nkan tosile fo ni ofurufu Eyin o mo nkankan nipa ofin yi, sugbon Sir Isaac Newton si sobe Ema gba. Otan, Itumo iyen ni wipe ema tele eyan to se pataki Gege na agudo gba Krsna bi Olorunlat'okan wa sugbon awon eyan pataki bi Caitanya, Rāmānujācārya, Śaṅkarācārya, awon eyan pataki ton toju ile-aye yi Nitorina eyin na gbudo gba be