YO/Prabhupada 0288 - Teba tin soro nipa Olorun semo isọtunmọ Olorun



Lecture -- Seattle, September 30, 1968

Alejo: Boya eti daaun si ibeere yi, mio gbo. Sugbon lati kekere wan ti ko mi wipe agbudo ni'fe Olorun lehin na mole ni'fe fun gbogbo nkan. Se Olorun ni Krsna?

Prabhupāda: Beeni. Se eyin ni Olorun toyato si Krsna? Se Olorun toyato si Krsna wa?

Alejo: Kini ibeere te wi? Oh...

Prabhupada: E gbiyanju lati mo nipa Olorun.

Alejo: Mio mo pe Olorun ni Krsna je.

Prabhuapd: Gbogbo nkan loni isọtunmọ. gege timo ba so wipe " ago ni mo mudani". isọtunmọ niyen Itumo ago ni wipe, nkan na si yika, o loju funfun pelu owo mejipelu orisirisi ila lati fi mo asiko. gege bayi moti salaaye fun yin gege na ounkooun teba fe mo nipa re,egbudo se isọtunmọ se mo isọtunmọ fun Olorun?

Alejo: Beeni. Mo rope, Ife ni Olorun je

Prabhupāda: isotunmo ko ni ife yi, ise ni ife je Beeni. mo ni'fe Olorun. Ife ni ise mi sugbon Olorun gbudo ni isotunmo, eyin na mo be. Sugbon eti gbagbe Nigbami awon elomi a so ipe " Alagabra ni Olorun je" Bawo la sele mo mo se l'agbara to? Teba so wipe " Okurin na la'gbara" egbudo ni bi eyan sele wan aduru agbara toni orisirisi ipo lowani eto oye bawo lesele mo bi Olorun se l'agbara to? bawo lese siro agbara na? gege na iwe mimo bibeli so wipe " Olorun si wipe "mo pase lati da iseda" se otooro ko niyen? aggbar Olorun niyen O fenu de gbogbo iseda aye yi Sele se yen?7 kasowipe Gbẹnagbẹna le je sele sowipe " mo pase lati da aga ki aga na dede farahan? sole sese? kasowipe eyin ni aṣelọpọ ago yi sele sowipe " mopase lati da ago, kosi dede farahan lesekese kole sese. Nitorina ni Oruko Olorun se je satya-saṅkalpa. Satya-saṅkalpa. Itumo Satya-saṅkalpa ni wipe ounkooun to ba ro l'okan ma sele lesekese Awon to si ni agbara lati ise Yoga awon na le se nkan bawonyi, kole dabi Olorun sugbon o jo gan Ti yogi ba ti l'agbara na ounkooun to ba fe lesekese loma wa Itumo satya-saṅkalpa niyen.orisirisi apeere lowa. gege bi awon oni sayeni nisin wanti da awon ero ton fo lori ofurufu lati fi de Osupa gbogbo awon oni sayensi lati Orile-ede America, Russina lon gbiyanju lati se Sputnik ton da ma pada wa. Sugbon seri agbara Olorun aimoye isogbe-orun to da ton fo lori ofurufu bi owu. agabra niyen gege na ti oniranu kankan ba sowipe Olorun ni oun je, Asiwere ni eni na Alagbara ni Olorun je. Ema fara we Oluwa. Kosi besele farawe Olorun, sugbon awon iranu kan sele na "olorun ni gbogbo wa, Olorun nimi, Olorun le je - Aja ni awon ton soro bayi teba le fi agbara Olorun hon, nigbana ele soro e sise ke to bere sini soro. Iru agabra wo le ni gan? Alagbara ni aolrun je, awa si wa labe agabra re gege na abajade to wa ni wipe agbudo di iranse Oluwa Agbudo di iranse fun pelu ife gege bi awon omo-okurin wanyi sen sise fun mi Ounkooun tin ba so, wan ma se. Kilode? Omo Orile-ede India nimi, alejo nimi Odun meji si meta teletele awa o mo ara wa kilode ton sen se? Nitori ife taba di iranse itumo re ni wipe amu ife jade lehina afi teba nife fun Oloru kosi besele sise fun ibikibi teba sise nitori ife loje Gege bi iya ton sise fun omode re. Kilode? Ife gege na ile-aye wa a ni ilosiwaju taba nife to da fun Olorun Egbudo ko lati se. Imoye Krsna niyen alabasepo pelu krsna gege mi mose nife awon okurin tin mon ko, awon na si nife mi. Kilode? Nitori Krsna