YO/Prabhupada 0291 - Mio fe teriba fun enikankan, ko wunmi kin teriba - Aisan teni niyen



Lecture -- Seattle, September 30, 1968

Prabhupāda: ehen?

Okurin: Sele salaaye itumo igboran?

Tamala Krsna: E salaye igboran.

Prabhupada: igboran, o rorun. Eyan to ni igboran le je Eyin o mo itumo igboran se nkan to le ni? se eyin oni igboran si enikan?

Okurin: Odabe..

Prabhupad:Beeni, Egbudo, gbogbo wa la gbudo ni igboran

Okurin: Sugbon ni oro awon nkan mimo moni igboran bibeko mi o....

Prabhupada: Nialakoko oye ke mo itumo ile-aye toyasi mimo ninu oro emi, eyin na ni igboran nitoripe iwa yin niyen ninu emi, kini itumo emi ati taye?

Okurin: Gege mi ara mi se wa nibi , nisin timo ba ni ise tin mon se, mole sowipe moni igboran si Oga mi, sugbon emi mi.. Mio rope emi mi ni igboran fun Oga mi Nkan ti mo ro ni wipe leto emi, egbe nimo je pelu oga mi

Prabhupada: Beeni. Osi da pe inu yin odunsi Oga yin. Abi beko?

Okurin: Rara. beko.

Prabhupada: Bawo wani?

Okurin: Mi o..

Prabhupada: Enikeni

Okurin: Mio rope... Sese dandan ni wipe ki jowu si Oga mi nitoripe o si gaju mi sugbon mo ro wipe gege bi awon eda, egbe ni gbogbo wa je Semo, imoye timo ni niyen Mio rope oye kin teriba fun enikankan , mio de fe k'eni kankan teriba fun mi

Prabhupad: Kilode? Kilode? Kilode ti iwo o fe ki awon eyan teriba?

Okurin: Nitoripe Kosi nkan to je mi

Prabhupad: Aisan to wa niyean pelu agidi la fin teriba, koseni to de fe teriba. Aisan to wa niyen

Okurin: Koseni to sope dandan ni kin teriba.

Prabhupada: Beeni.

Okurin: Oun ko lo so wipe kin teriba Mo wa ni temi, oun na wa lodo tie

Prabhupada: Rara. E gbiyanju lati ni oye. Ibeere toda le beere. E sowipe mio fe teriba. Beko?

Okurin: Beeni.

Prabhupad: Beeni. kilode?

Okurin: Nitoripe mio ro pe enikan da jumi lo..

Prabhupad: Aisan to wa niyen. Eti fun ara in so aisa ton se yin Aisan ile-aye niyen Gbogbo eyan fe d'oga, Koseni to fe teriba Gbogbo eyan lon ronu bayi, eyin ni kankan. Eje kin paari aisan to wa niyen. Aisan ti yin tabi temi ko. Aisan gbogbo wa ni wipe " kilode te fe kin teriba?" Kilode te fe kini igboran si yin? Sugbon gbogbo iseda aye sin f'agbara tewa ka teriba. Ta lo fe ku nibi? Sugbon awon eyan sin ku? sele daun si ibeere na?

Okurin: Kilode ti awon eyan sen ku?

Prabhupad: Beeni. Koseni to fe ku

Okurin: Emi ro pe oro isedale niyen.

Prabhuoada: Dakun gbiyanju lati ni oye.. Se iwo ni igboran si eko oniye Kilode tewa sowipe efe se bo se wun yin?

Okurin: Mo rope..

Prabhupada: Nkan ton ro, ko sogbon nibe. nkan ti mon so niyen. aisan teni niyen

Okurin: eso wipe mo dawa?

Prabhupad: Beeni, asise wa ninu nkan ten ro.

Okurin: asise?

Prabhupada: beeni. Egbudo ni igboran. Egbudo teriba Ti iku bade sele sowipe " Mio fe ni igboran si yin" Nitorin egbudo ni igboran

Okurin: Beeni moni igboran si Olorun

Prabhupada: Rara. Gbagbe Olorun na. nkan ogbon la wan so nisin.

Okurin: Krsna..

Prabhupada: rara, ma soro Krsna iyen ti jinaju fun e Mo fe ke ni oye pe koseni to fe ku sugbon gbogbo wa lama ku. kilode?

Okurin: Kilode ti moma ku?

Prabhupada: Beeni. Nitoripe egbudo ni igboran.

Okurin: Beeni

Prabhupada: Beeni. Se ti ripe egbudo ni igboran si awon to gaju yin lo Kosi besele sowipe " mo le se bo sewunmi, mio ni teriba fun enikankan" Aisan yi ni wipe eyin ronu pe " mio fe teriba fun enikankan"

Okurin: Kilode tefe kin....

Prabhuada: Rara, nialakoko, oye ke mo iru aisan teni,lehin na ale wa ogun funyin

Okurin: Ta le fe kin teriba fun

Prabhupada: Gbogbo eyan leyin teriba fn, Eti teriba si Iku, eti teriba fun aisan, nkan teyin ti teriba fun po gan. Sugbon pelu agidi sugbon esi rope " Mio le teriba fun enikankan" Nitoripe eyin o fe se, gege dandan le ma se Egbudo teriba. Kilode tese gbagbe ipo yin. aisan tani niyen nitorina lesen bere " kilode ton sowipe dandan ni lati teriba" nisin agbudo wadi " se mo li ni idunnu tin ba teriba?" kosi besele fi ipaari si igboran si awon to juwa lo teba teriba si Krsna ati awon alabasepo re ema ni idunnu. E yewo Egudo teriba. Teba ko ati teriba fun Krsna ati awon alabasepo re, ema teriba fun nkanmi, maya. Kosi besele se bose wunyin.. gege bi omode ton teriba fun awon obi re, inu re si dun Iya re asi sowipe " Omo mi wa joko". Beeni Inu re ma dunsi. Bose je niyen Egbudo wa ibi toye ke teriba, otan. Krsna niyen je Kosi besele fi ipaari si. Egbudo wa ibi toye ke teriba, otan. teba si ko te ro pe " Mio le teriba fun enikankan, mole se bo se wunmi", ema jiya gan. Egbudo wa ibi toye ke teriba, otan. Ekorin