YO/Prabhupada 0293 - Orisirisi Rasa mejila, yẹyẹ



Lecture -- Seattle, October 4, 1968

eda to lewa ju ni itumo Krsna. " Osi lewa si awon Ololufe re, Osi lewa si awon alakowe" O lewa si awon oloselu, O lewa si awon onisayensi, osi lewa si awon ole. awon Ole gan nigbati Krsna wole si ile Kamsa, orisirisi awon eyan lon ri pelu oju toyato si rawon Awon ton wa lati Vrndavana, omo-obirin lon je Wansi Krsna bi " eda to lewa ju" Awon jagunjaun si ri bi aruwo-ara wansi ri Krsna sugbon wan sowipe " aruwo-ara leleyi" kosi beyan se fe lagabara to , ti ara ba kan oma de le ni wansi ri Krsna bi aruwo-ara, awon jagun jagun Awon agbalagba si ri Krsna bi omode tolewa Gege na eyan leni abasepo pelu Krsna bose fesi awon rasa to mejila gege bi awon osere, nigbami wan le ni orisiri nkan, nigbami wan le se nkan to le funyan ni ibanuje nigbami wanle se ibi ti enikan fi ku pa elomi, inuwa asi dun taban wo Orisirisi eyan lo wa, gege na orisirisi idaraya lowa ikan ninu awon omo-okurin timon ko ni Ilu Montreal si sowipe Baba re feran ija akomalu ni Orile-ede Spain Tonba de ti pa akomaalu na, inu re sin ma dun - Orisirisi okurin elomi asini ibanuje to wo irunkan bayen, inu elomi asi dun se ribayi? Krsna le gbawan laaye teba nife awon nkan tole deruba eyan, Krsna le farahan bi Nrsimhadeva "Ah" (Erin) Beeni Teba si fe ri Krsna bi ore to dara gan, Vamśī-dhārī, Vṛndāvana-vihārī. lo je teba fe Krsna gege bi omode to lewa, Gopala na loje Teba si fe Krsna gege bi Ore, Arjuna lo je, gege bi Arjuna ati Krsna orisirisi ihuwasi mejila lowa Krsna sile ba wa ni asepo lori gbogbo wan, nitorina oruko je Akhila-rasāmṛta-sindhu. Akhila-rasāmṛta-sindhu. Itumo Akhila ni gbogbo agbaye, itumo rasā ni ihuwasi, ati okun gege bi eyan to ban wa omi to ba los'okun omo to po wan be Kosoro iwonba omi wo lowa nibe gege na teba fe nkan teba si sumo Krsna, nkan te fe ema ri lai si opin Nitorina Bhagavad-gita si sowipe yaṁ labdhvā cāparaṁ lābhaṁ manyate nādhikaṁ tataḥ. teyan ba le de Ijoba Olorun asi ni itelorun, lehin na a sowipe " Ko si nkan ti mo fe mo" Moti ni idunnu to pe. Yaṁ labdhvā cāparaṁ lābhaṁ manyate nādhikaṁ tataḥ yasmin sthite. teyan ba de ti de ipo to gaju kiloma sele? Guruṇāpi duḥkhena na vicālyate (BG 6.20-23). idanwo to le gan lowa nbe

Orisirisi apeere lowa ninu Śrīmad-Bhāgavatam Ninu Bhagavad-gita eleri pe awon Pandava si jiya gan, sugbon wansi ni igbagbo Kosi igba ton so wipe " Krsna orewa lo je Kilode ta sen jiya bayi? rara. Nitoripe, wansi ni igboya ninu gbogbo isoro to sele si wan ama ni isegun nitoripe Krsna wa peluwa Nitoripe Krsna wa peluwa. Igboya wa niyen. Nkan ton pe ni śaraṇāgati, teriba.