YO/Prabhupada 0294 - Idi mefa lati teriba fun Krishna



Lecture -- Seattle, October 4, 1968

Ona mefa leyan le gba ati teriba si krsna Ona kan niwipe eyan le nigbago pe " Krsna ma gbamila" gege bi omokekere to mo pe iyare wa. kosi nkan tole sele soun Igboya. Moti ri Ma si fun yin ni apeere kan Ni Ilu Calcutta nigbati mo si kere mosi ni irin ajo omomi-okurin tosi kereju si wa pelumi. Nigbana omo odun meji tabi meji abo loje eni tosin gbowo si beere lowo re " funmi lowo e" Nialakoko omomi si daun " mi o lowo". Okurin ton gbowo si sowipe " wa bole ni oko na" lesekese omomi sowipe " Baba leleyi" (erin) Seri. " Kosi bosele sofunmi kin bole, baba mi wanbi" Se tiri bayi? oroinuokan niyen. teba si sumon Krsna, kosin nkan tole deruba yin mo Otooro niyen E gbiyanju lati ni ibukun to gaju layeyi, Krsna kini Krsna so? Kaunteya pratijānīhi na me bhaktaḥ praṇaśyati (BG 9.31). " Kaunteya mi, omo Kunti, Arjuna, so fun gbogbo agbyae awon elesin mio le se asegbe" kosi bon sele se asegbe. Kaunteya pratijānīhi na me bhaktaḥ praṇaśyati.

Gege na opolopo ese-iwe ninu Bhagavad-gita mosi fe fun yin awon eri ninu iwe Bhagavad-gita nitoripe iwe na si gbajumo ni gbogo agbaye egbiyanju ati ka iwe na.. Krsna si sowipe:

ahaṁ sarvasya prabhavo
mattaḥ sarvaṁ pravartate
iti matvā bhajante māṁ
budhā bhāva-samanvitāḥ
(BG 10.8)

Talole s'adura si Krsna? Wan si salaye nibi, eyan to logbon ni itumo Budhā Ogbon Itumo bodha, eyan to logbon ni budha gbogbo eyan lofe ni imoye, Nibi eni Ile-iew giga Washington awon omo-ile iwe na si po gan. wan si ti wa keko gege na eni to ti gba imoye to gaju wansi pe ni budha bhāva-samanvitāḥ. Ayoti olopin ni itumo Bhāva Eyan gbudo logbon, sugbon ogbudo ni ayo temi wa na iru eyan bayi Krsna sowipe, iti matvā bhajante mām. "Iru eyan bayi lon sadura simi pelu ife" Eyan to logbon to si ni ayo atinu wa iru eyan bayi lonife Krsna tabi lole s'dura si Krsna kini di? nitoripe iti matva, "oti ni Oye" Oye kin? Ahaṁ sarvasya prabhavo (BG 10.8), Emi ni orisun gbogbo nkan, sarvasya oukooun teba mu wa, ema ri pe Krsna ni nkan na je Vedanta si sobe. Kini Brahman? Athāto brahma jijñāsā.