YO/Prabhupada 0302 -Awon eyan oni iwa igboran



Lecture -- Seattle, October 2, 1968

Prabhupāda: Awa nka iwe akeko Oluwa Caitanya ipade wa to kehin la beere, ama tesiwaju looni. s'ole ka fun wa? Beeni.

Tamāla Kṛṣṇa: Oju-iwe ogun, sugbon nibo le paari si?

Prabhupāda: Ka ibikibi toba fe. Otan. Beeni.

Tamāla Kṛṣṇa: O daa. " Ninu Bhagavad-gita, wanti sofun wa pe iwa adayeba ti gbogbo eda ni wipe emi laje. Nkan aye yi ko loje. Nitorina gege bi emi toje nkankanna ni oun ati Olorun, emi to gaju. Wan si kowa pe, taba fe ni idunnu agbudo teriba nitoripe ise wa gege bi emi niyen. itosona to kehin ninu iwe Bhagavad-gita niwipe agbudo teriba patapata. si Emi to gaju, Krsna, lehin na ale ni idunnu. Nibi Oluwa Caitanya se atunso otooro yi nigbato daaun si awon ibeere Sanatana sugbon kofun ni irohin nipa Emi bonse salaye ninu GIta.

Prabhupāda: Beeni. Oro towa niwipe, apejuwe lori ipo emi wanti salaaye repete lori re ninu Śrīmad Bhagavad-gītā. itosona to kehin ninu Bhagavad-gita, Krsna sowipe, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). Oti salaaye nipa gbogbo orisirisi eto yoga, orisirisi esin, ebo, ati imoye ipo t'olofin ara wa, pelu t'emi wa. Gbogbo eleyi loti salaaye ni Bhagavad-gita. Ni'paari o sofun Arjuna " Arjuna mi, nitoripe ewo je oremi taya taya, nitorina mose fe soro tose igboya ninu imoye Veda". Kini oro yi? "E teriba funmi". Otan. Awon o fe ni igboran, nitorina nkan ton ni lati ko pogan. gege bi omode, igboran lasan loni si awon obi re, inure si dun. kosi iwulo pe awa fe ni imoye basele gbe ninu ayeyi pelu alaafia. omode na ko moju itoju awon obi re, inu re sidun. imoye to rorun. Sugbon nitoripe awa ti ni ilosiwaju ninu awujo wa nitorina awon nkan to rorun bayi ko le yewa mo. Otan sugbon teba fese ariyanjiyan tio lori, kosi iru nkan bayi ninu egbe imoye Krsna awa sini iwe to po gan ni eto imoye sugbon egbudo gba ilana wa yi to rorun gan, Alagbara ni Oluwa, nkankannna laje pelu re, mogbudo ni igboran si, mogbudo teriba fun. ise mi niyen. Otan. Gege na Caitanya Mahaprabhu laisoro lori ipo wa, tabi imoye wa pelu eto yoga, lesekese lo beere lati so funwa pe ise gbogbo wa ni lati sise fun Olorun Ibeere akeko Caitanya Mahaprabhu niyen. Itumo niwipe, ibiti Bhagavad-gita paari si ibe ni akeko Caitanya Mahaprabhu ti beere.

Prabhupāda: Beeni, Tesiwaju.

Tamāla Kṛṣṇa: Lati ibi ti Krsna ti paari lo beere Awon elesin giga ti sofun wa pe Krsna fun arare ni Oluwa Caitanya lati ibi to paari itosona re ninu Gita lo beere sini salaaye fun Sanatana. Oluwa si sofun Sanatana, " ipo re ni wipe emi mimo loje" iwo yato si okan re tabi ara re o si yati si ogbon re, tabi igberaga toni Idanimo toni ni wipe " iranse Olorun Krsna loje".

Prabhupāda: awon oro kan tose pataki leleyi, ninu eto idanimo arawa, awon eyan ton feran aye yi, wan rope " Arami nimo je". Arami nimo je, iye-ara wa ni itumo ara wa nitorina igbadun iye-ara mi ni itumo igbdun Idanimo ara wa to kere ju leleyi. Ara wa, okan wa, pelu emi wa gbogbowa lon sepo lati ni " eda eyan" awon meta lon sepo tanwa pe ni "ara wa" ni imoye idanimo arawa to kereju, gbogbo wa lan rope nkanna ni ara wa pelu emi. ninu ipo to ga die si, awn rope Okan wa pelu Ogbon wa pe nkanna lon je si emi wa. sugbon, emi gaju ara wa lo, osi gaju okan wa lo, osi ga ju ogbon wa lo Ipo to wa niyen. awon eyan ton wa lori ipo to kere ju nipa idanimo arawa, asegbe niwan. awon ton wa lori ipo okan ati ogbon, awan alakowe ati akewi niwan. wan soro pupo, sugbon nkan ton salaaye ko ni iwulo. sugbon teba de ipo t'emi togaju, ise farahun Oluwa niyen je. Caitanya Mahaprabhu ti salaaye fun wa.