YO/Prabhupada 0304 - Maya Cannot Cover the Supreme Whole



Lecture -- Seattle, October 2, 1968

Prabhupāda: Tesiwaju lo.

Tamāla Kṛṣṇa: "Iparapo ati iyato yi wa ninu gbogbo ibasepo. laarin awon eda ati Eda to gaju."

Prabhupada: Ninu eto iparapo ati iyato yi, egba fun apeere , ile. Eyokan le sowipe, " Oh, mori wipe omi lo wa n'be." elomi le sowipe, " Rara. Ile lo wa nibi ton so." Ikankanna ati iyato. Ikankanna ati iyato. Ipo wa niyen.. nitoripe emi laje ati Krsna, Olorun, emi loun na je... Emi kan soso loje sugbon iwonba die ninu emi re nimo je. Gege bi orun, ati ina lati orun, awon molekulu ninu ina, ina orun na lonje. Akojopo awon molekulu yi lan fun wa ni ina lati orun. gege na awon na tanna bi orun sugbon awon dabi orun na nitoto. Awon molekulu wanyi lati inu orun, wan o to orun na ni iwonba to je, sugbon amuye kanna lonni. Gege na, eda la je, Iwonba kekere ninu emi to gaju, Krsna tabi Olorun, lawa na. Nitorina lasen tanna. amuye kanna lani. Gege bi wura kekere se je wura. Irin ko loje. gege na, emi lawa je, nitoria nkankana niwa. Sugbon nitoripe mo kere gan.. gege bi apeere ti mo fun yin. Iwonba kekere ri, omi le bo mole. Sugbon ile to bi na, kosi l'omi. Gege na, maya le bo awon emi kekere yi sugbon maya o le bo emi nla to gaju. gege bi apeere kanna, Orun ati ina-orun. awon sanma le b o ina orun ton ran. sugbon teyin ba wonu oko-afefe, te gu ori awon sanma, Eyin na ma ri wipe kosi sanma kankan tonbo ina orun yi. Awon sanma yi o le danikan bo orun. gege na, maya o le bo emi to gaju. Maya le bo awon patikule ti Brahman. Alaye Mayavadi wipe: "Nisin may ti bomi. Leseke setin ba jade ninu idabo yi, ma d'odindin...." Nkankan laje pelu Odindin yi. gege bi ina orun ati Orun na, kosi iyato kankan ninu amuye ton ni. Ibikibi ti orun yi ba wa, ina orun na ma wa, sugbon awon patikulu kekere wanyi, kosi bonsele to odindin orun. Caitanya Mahaprabhu ti salaaye ninu ese-iwe to kan.