YO/Prabhupada 0308 - Function of the Soul is Krishna Consciousness



Lecture -- Seattle, October 2, 1968

Okurin(2): bawo lasele ko okan wa leeko?

Prabhupada: eko toyeke ko leleyi. E sise fun Krsna. Ise to daju leleyi. gege bi orin kiko, omo odun mewa gan le se. Okan re wa lori ohun Hare Krsna. Awon iye-ara re, ese tabi owo re, gbogbo wan sise, wan jo. gege bayi loye ka ko okan wa leeko, pelu iye ara wa ninu ise imoye Krsna nigbogbo igba. Eleyi ma jeke wa ni pipe. Gbogbo eyan lole se. Kosidi pe ejoko sibi kan teyin sasaro lori nkan. lesekese teba korin Hare Krsna, beena l'okan yin ma yipo, lesekese lema ranti Krsna, awon ilana Krsna, ise Krsna, gbogbo nkan. Egbudo keko na.

Okurin(2): beeyin seje ina orun, kasi sobe...

Prabhupada: Beeni.

Okurin (2): Seyin rope eyin je bayi?

Prabhupada: Kilode? Eda nimoje.

Okurin(2): Teyin ban ronu seyin man ronu nipa Krsna?

Prabhupada: Mole kere sugbon, eda sii nimi. Mosi l'agbara lati ronu, lati ni ifarasi, lati sise tokan. Awa na n'se be. Eyan ni gbogbo wa je. Eti wa si lat'okan yin. Koseni kankan to mu yin wa ni dandan, ele lo teba fe. Awon eyan imi ma wa, awon imi o ni wa, awon imi ma wa lojojumo. Kilode? Ele kere sugbon, eda sini yin. Ninu ipo tewa yi, ele se bese fe. Aye po fun yin. teyin ba wa di eda, to wa ninuu emi tan, se iru aye tema ni lati se besefe. kosi nkan to ba teba kere, ina mimo leje. Seyin o riwupe, ina kekere yi kosi ologun kankan, tabi sayensi iwosan tole waadi, sibi ti emi yi wa, sugbon emi na wan'be. Oto oro niyen. Lesekese ti emi yi ba jade kuro ninu ara, koni iwulo kankan mo. E waadi nipa nkan kekere yi to se pataki gan. Kolese se, nitoripe o ti kere ju, fun oju yin tabi awon maikroskopu, tabi eyikeyi ero teba fe Nitorina lo sen sowipe ko s'emi kankan. Sugbon awon eyan yi o le salaaye nkan to f'ara le. nkan kekere yi si lagbara toje pe, fun igba toba wa ninu ara wa, asi je ki ara wa, wa laaye, ati ko lewa. lesekese toba lo, ara na ma bere sini baje. Gege bi abere. Iwonba die nikan le jek'ara wa ya. Iru nkan bayi loje, o lagbara gan. Eyin o mo iru agbara t'emi yi ni. Nkan toye ke ko niyen. Imoye ara-eni niyen. Ilana lati sasaro, pe awon joko ni ibi to palolo, nkan fun awon eyan tio logbon rara niyen. Awon bayi ni lati sasaro kon beere, " Se ara mi nimo je?" Eyin ma ri bayi, " Rara. Ara mi ko moje. Moyato si ara mi." Toba wa sasaro si: Ti moba yato s'ara mi, kini nkan to wa leyin gbogbo ise ara yi? Se nkan kekere to wa ninu ara mi lon je ko sise. bawo ni ara yi sen dagbasoke? Se nitroripe o wa ninu ara mi. gege bi omode yi, osi ni ara omo kekere. Toba ya, omode na ma dagba asi di okurin ni odun mẹrin-le-logun. toba de ya, ara yi ma lo, imi a tun de. Bawo leleyi sen sele? Nitori emi kekere yi to wa ninu ara re. Sugbon ti emi yi ba kuro tabi toba jade, ara yi o le dagba mo. awon eto toye ke sasaro le, leleyi. Sugbon teyin ba mo wipe " Ara mi ko nimi, emi ni mo je," ipo to tele niwipe " Kini ise emi yi?" Ise emi yi ni imoye Krsna, ise ninu imoye Krsna. Ni asiko tawa yi, agbudo gba ise emi yi; lehin na awon nkan to ku ma wa lesekese. Ni asiko tawayi kolese se pe elelo sibi to daake, ke joko ke sasaro... Kolese se ni asiko tawayi. Kolese se. Teba gbiyanju lati se, ikuna nikan lema ri gba. Nitorina egbudo gba ilan yi s'okan,

harer nāma harer nāma harer nāma eva kevalam
kalau nāsty eva nāsty eva nāsty eva gatir anyathā
(CC Adi 17.21)

Ninu asiko Kali yi, kos'ona abayo 'mi lati le ni imoye nipa eni taje afi kiko orin Hare Krsna. Nkan to wulo niyen, otitooro.