YO/Prabhupada 0314 - Not So Much Attention for the Body, but Full Attention for the Soul



Lecture on SB 6.1.10 -- Los Angeles, June 23, 1975

Ninu aye tawa yi, ija ati idanmu lo wa nitorina loseje Kali Ninu aye tawayi, ona kan soso lowa: hari-kirtanat. Egbe sankirtana yi ni hari-kirana, Hari-kirtna.. Kiko orin nipa ogo Olorun ni itumo Kirtana wansi ti salaye ninu Srimad- Bhagavatam:

kaler doṣa-nidhe rājan
asti hy eko mahān guṇaḥ
kīrtanād eva kṛṣṇasya
mukta-saṅgaḥ paraṁ vrajet
(SB 12.3.51)

Wansi ti salaaye nipa Śrī Caitanya Mahāprabhu ninu Śrīmad-Bhāgavatam tviṣākṛṣṇaṁ...

kṛṣṇa-varṇaṁ tviṣākṛṣṇaṁ
sāṅgopāṅgāstra-pārṣadaṁ
yajñaiḥ saṅkīrtana-prāyair
yajanti hi sumedhasaḥ
(SB 11.5.32)

Nitorin aise kini tani niwipe agbudo saadura si Caitanya Mahaprabhu. Ni alakoko agbudo saadura si Caitanya Mahaprabhu pelu awon alabasepo re, lehin na, Guru-Gauranga, lehin na Radha-Krsna tabi Jaganatha. Nitoripe asiko Kali lawa, yajñaiḥ saṅkīrtana-prāyair yajanti hi sumedhasaḥ, Teaba sise sankirtan yi fun adura igba teba lese niwaju Oluwa Caitanya, aye yin ma ni ilosiwaju. Kosi nkan imi te fe. Nkan ton salaaye niyen: yajñaiḥ saṅkīrtana-prāyair yajanti hi sumedhasaḥ.

Awon eya ton longbon, wan ma tele ona yi. Teba se korin si, beena ni okan yin ma mosi. Ceto-darpaṇa-mārjanam (CC Antya 20.12). Nkan toye ke se niyen. Nkan alakoko leleyi nitoripe laisi ceto-darpana-marjana aye emi wa o le bere afi ti digi okan wa ba mo. Sugbon ona lati fi nu leleyi. teba si korin Hare Krsna tokantokan, nkan alakoko to ma sele niwipe okan yin ma mo. Lehin na ele ri fun ara yin, nkan ti ise yin je. Ti okan yin o ba mo Kosi besele nu pelu awon ebo Kolese se. Nitorina.. Pariksit Maharaj si logbon gan. O sowipe, prāyaścittam atho apārtham Apa, apa, itumo re ni " nkan buru", itumo artha ni "itumo". " koni itumo kakan." Lesekese lo fi na prāyaścittam apārtham sile. " Kini iwulo to wa nbe? Asi wa ninu idoti. Kole nu okan re." Orisirisi nkna to doti wa nuinu okan re: " Bawo ni mose fe tan awon eyan je, bawo ni mose fe gbadun, bawo nimose fe lo ba awon asewo, kin sin moti." Awon nka wanyi wa ninu okan re. gege na pe alo si ile-adura lati lo sadura lori ese wa , ko le ranwa lowo. Abbudo mu eto yi ni pataki, snakirtanam. Ceto-darpaṇa-mārjanaṁ bhava-mahā-davāgni-nirvāpaṇam (CC Antya 20.12).

Nkan alakoko niwipe agbudo nu okan wa. Nkan ikeji to wa niwipe bhava-mahā-davāgni-nirvāpaṇam. t'okan yin b amo, lehin na lele mo ipo yin ninu aye yi. sugbon pelu okan to doti kosi besele mo. T'okan yin ba mo ele mo wipe " ara mi ko ni mo je. Emi nimi. Gege na kini mon se fun ara mi? Emi nimi. Ara mi ko ni mi moje. Mon fo ara mi, fun ebin pa emi mi. Nkan ton sele niyen. Itumo awujo wa ni wipe, ka toju ara wa dada lai mo nkankan lori emi wa. Awujo ile aye tawa. Egbe imoye Krsna wa, si foju si emi wa, awa o foju si ara wa. Odikeji ni imoye Krsna yi je. Kosi bonsele ni oye nipa egbe yi. Egbe nipa eto emi loje. Konse egbe lasan Nitorina nigbami awon eyan man rowipe "ara wa o ya" Wan o kin jeran nitorina ni bayi bayi sen sele. Awon ara yi o dawa laamu, awon nkan emi ni eto wa. Nitorina ni awon eyan yi o se ni oye ni pa wa. Awon eyan le mo, wan le ma mo na - kosi nkan to baje nibe. Eyin e foju si Kirtana yi ke fi ipari si ile-aye yi. Ese pupo.