YO/Prabhupada 0317 - We are not Surrendering to Krishna. This is the Disease



Lecture on BG 4.7 -- Bombay, March 27, 1974

E gbiyanju lati mo nkan ti esin je. Olorun kan soso lowa. Kosibi kankan t'Olorun sowipe esin leleyi, esin ko ni yen." Olorun, Bhagavan Krsna so ni Bhagavad-gita... yadā yadā hi dharmasya glānir bhavati (BG 4.7), paritrāṇāya sādhū... Ni ila to tele os sowipe,

paritrāṇāya sādhūnāṁ
vināśāya ca duṣkṛtām
dharma-saṁsthāpanārthāya
sambhavāmi yuge yuge
(BG 4.8)

se mejeji t Krsna niyen. Nitoripe o ti salaaye, bhūtānām īśvaraḥ. " emi ni olori gbogbo awon eda." Nitorina ti awon awon asise ba wa lona dharma, oun lon fiyaje awon eyan tabo ko si fun wan ni ibukun. Paritrāṇāya sādhūnāṁ vināśāya ca duṣkṛtām. Nkan meji gege bi ijoba sen toju awon omi-ilu to daa, asi fiya je awon omo-odaran. Ise meji ijoba niyen. Ijoba to gaju ti Krsna... Nitoripe nibo ni oro yi t wa? Ijoba asi toju awon om-ilu to da, tabi ko fiyaje awon omo-odaran. Itumo dharma niwie, gege bi Krsna se so ninu Bhagavad-gita, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). dharma leleyi. dharma leleyi. Dharma ni iwa to ye ka ni.

Nitoripe gbogbo wa gbudo terib afun enikan. E wo gbogbo eyan daada. O ni eni kan to gaa ju lo. O le je awo ebi re, iyawo re, ijoba re , awujo re, oniselu re, ibikibi teba lo, iwa lati terib ayi wa. Kosi besele sa a fiile. Oro taba Alamodaju Kotovsky so ni yen ni Moscow. Mo bere lowo re, " Nisin eyin ti ni imoye Kommunist yin. Awa n ani imoye Krsna wa. Kini iyato laarin awon imoye wanyi? Eyin ti teriba fun Lenin, awa ti teriba fun Krsna. Kini iyato to wa nbe?" Egbudo teriba. Kosejo ibi ton teriba. Toba teriba sib to daa, gbogbo nkan ma daa na. to basi teriba sibi ti o da , gbogbo nkan ma baje na. Imoye to wa niyen. Awa ti teriba.

Śrī Caitanya Mahāprabhu ti salaaye Jīvera svarūpa haya nitya-kṛṣṇa-dāsa (CC Madhya 20.108-109). awa ti teriba, sugbon fun Krsna ko. Aisan to wa niyen. Aisan to wa niyen. Itumo egbe imoye Krsna yi ni lati fun awon awon ni iwosan. E fun wa ni iwosan. Krsna sowipe yadā yadā hi dharmasya (BG 4.7). Awon dharmasya glanih, isekuse ninu eto esin, ti awon isekuse ba wa, Krsna sowipe, tadātmānaṁ sṛjāmy aham. ati abhyutthānam adharmasya. Awon nkan meji to wa niyen. Ti awon eyan o ba teriba fun Krsna, wan ma da orisirisi nkan sile. Awon asiwere to po ma teriba sibe. adharmasya niyen. Lati teriba fun Krsna ni itumo Dharma, sugbon dipo kon teriba fun Krsna, wan fe teriba fun ologbo, aja, ati orisirisi nkan. adharma niyen.

Krsna o da esin Hindu tabi esin Musulman tabi Kristianni. rara. O wa lati da esin to daju sile. Itumo esin to daju niwipe agbudo teriba fun eni to daju. Esin to daju niyen. Awon eyan jiya. Onikaluku ni ero tie, osi ti teriba si be. ko je oselu, awujo, eto-oro aje, esin, ounkooun. Gbogbo eyna ni nka tie. Awon olori si wa nibe. Lati teriba ni ise tawani.Oto oro niyen. Sugobn awa o mo ibi to ye ka teriba si. Nkan to le niyen. Nitoripe awon eyan o mo'bi to ye kan teriba si nitorina ni gbogbo wahala yi sen wa. Awa teriba sibi tio ye. Nisin awon apa oniselu to congress ati ti kommunist." Efi gbogbo awoj oro oniselu yi sile. Kini iwulo pe eyin fi apa oniselu kan sikeji? Nitoripe ibikibi teba wa, awon eyan yi o teriba fun Krsna. Afi teryin ba teriba fun Krsna ko si besele ni alaafia kankan. oro to wa niyen. Pe E kuro ninu koko sori ina, kole ranyin lowo.