YO/Prabhupada 0319 - Accept God, Your Position as God's Servant and Serve God



Room Conversation with Sanskrit Professor, other Guests and Disciples -- February 12, 1975, Mexico

Alejo(4): Se esin nitumo dharma?

Prabhupada: Rara. Ise apinfunni nitumo dharma. varṇāśrama-dharma. Agudo fi iyne gan sile. Itumo iyen niwipe agbudo ni imoye Krsna ni kan. O sowipe, sarva-dharmān parityajya. Ni alakoko, o sowipe dharma-saṁsthāpanārth. Beeni, Yuge yuge sambhavāmi. Nisin, O sowipe " Moti wa lati tun eto esin se." Ni ipaari losowipe sarva-dharmān parityajya. Itumo iyne niwipe, gbogbo awon esin yin, kosi eyi to daju nitorina ni Bhagavata se sowipe dharmaḥ projjhita-kaitavo 'tra (SB 1.1.2), gbogbo awon esin eke, ati fi wan sile." Esin eke, kin itumo iyen? Gege bi wurs Teba fi wura sinu owo Hindu, sema pe ni wura Hindu? gege na, igboran si Olorun nitumo esin. Gege na nibo ni esin Hindu wa? Nibo ni esin Krsistianin wa? Nibo ni esin Musulman wa? Olorin wa ni ibiki, awa gbudo gboran si Olorun. Esinkan soso to wa niyen. Kilode tonse da awon esin orisirisi wanyi, esin Hindu, esin Musluman, esin Krsitiani.. Esin eke nigbogbo wan je, Igboran ni esin to daju... Dharmaṁ tu sākṣād bhagavat-praṇītam (SB 6.3.19). gege bi ofin ijoba. Kosi besele sowipe ofin Hindu leleyim tabi ofin Kristiani leleyi, fun gbogbo eyan l'ofin wa fun. Igboran si'joba. Ofin niyen. gege na, igboran s'Olorun nitumo Esin. Gege na eyan tio bani imoye nipa Olorun, nibo loro esin se fe wa? Esin eke niyen. Nitorina ninu Bhagavata ema riwipe, dharmaḥ projjhita-kaitavo 'tra: (SB 1.1.2) " gbogbo awon esin eke wanyi, ati tiwan segbe kan." Krsna de ti salaaye nkankana, sarva-dharmān parityajya: (BG 18.66) efi gbogbo esin eke yi sile. E teriba funmi. Esin gidi leleyi." Kini iwulo pe eyin so isokuso lori awon esin eke wanyi, Esin ko leleyi. Ofin eke na loje. Kosi besele da ofin eke sile. Ijoba lon da ofin sile. Gege na, ase Olorun nitumo esin. Esin niyen je. Teba le tele, elesin niyin, teyin o ba le tele, esu leje. Eji ki awon nkan rorun bayi, Inu gbogbo eyna ma dunsi. Imoye Krsna yi wa lati jeki gbogbo wan nkan rorun. Egba pe iranse Olorun leje, ke sise fun Olorun. Otyan